Ní ìmọ̀ ìṣirò, Sendov's conjecture, nígbàmíràn wọ́n má a ń pèé ní Ilieff's conjecture, nííṣe pẹ̀lú ibi tí àwọn root àti àwọn ojú ibi iṣẹ́ polynomial ti complex variable. Wọ́n sọọ́ lórúkọ Blagovest Sendov.

Conjection yìí sọ pé fún polynomial

pẹ̀lú gbogbo àwọn  r1, ..., rn inú unit disk |z| ≤ 1, ìkànkan àwọn n root tí ìjìnasí wọn kò ju ẹyọ kan lati ojú kan.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  • G. Schmeisser, "The Conjectures of Sendov and Smale," Approximation Theory: A Volume Dedicated to Blagovest Sendov (B. Bojoanov, ed.), Sofia: DARBA, 2002 pp. 353–369.

Àwọn ìjápọ̀ látìta

àtúnṣe
  • Sendov's Conjecture by Bruce Torrence with contributions from Paul Abbott at The Wolfram Demonstrations Project