Serge Haroche
Serge Haroche (ojoibi 11 September 1944)[1] je is a French asefisiksi ara Fransi to gba Ebun Nobel ninu Fisiksi odun 2012 pelu David J. Wineland fun “awon ona tuntun idanwo to se lo lati se iwon ati ifowoyipada awon sistemu quantum kookan”, to je nipa iwadi eruku imole, eyun awon fotoni.[2][3] Lati 2001, Haroche je Ojogbon ni ile-eko giga Collège de France, ohun si ni Alaga Eka-Eko Fisiksi Quantum ni ibe.
Serge Haroche | |
---|---|
Serge Haroche (May 2009) | |
Ìbí | 11 Oṣù Kẹ̀sán 1944 Casablanca, Morocco[1] (then a French protectorate) |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Fransi |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Pierre-and-Marie-Curie University Collège de France |
Ibi ẹ̀kọ́ | École Normale Supérieure Pierre-and-Marie-Curie University (Ph.D.) |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | CNRS Gold medal (2009) Nobel Prize for Physics (2012) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Serge Haroche – Biographical". nobelprize.org. Retrieved 11 October 2012.
- ↑ "Press release – Particle control in a quantum world". Royal Swedish Academy of Sciences. Retrieved 9 October 2012. Text "title" ignored (help)
- ↑ Àdàkọ:Cite doi