Fọláṣadé Noimat Ọkọ́ya (bíi ni ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, oṣù kẹrin ọdún 1977) jẹ́ aláàkóso fún ilé-iṣẹ́ Eleganza Group èyí tí okọ rẹ̀ gbé kalẹ̀.[1][2][3]

Shade Okoya
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kẹrin 1977 (1977-04-25) (ọmọ ọdún 47)
Lagos State, Nigeria Protectorate
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Businesswoman
TitleManaging director, Eleganza Industrial City
Olólùfẹ́
Rasaq Okoya (m. 1999)
Àwọn ọmọOlamide Okoya

Subomi Okoya

Oyinola Okoya

Wahab Okoya
Websitewww.shadeokoya.com

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Folashade ní ọjọ́ kẹẹdọgbọn, oṣù kẹrin ọdún 1977 sí ìdílé Àlhájì Tajú àti Àlhájà Nimosat Adeleye sí ìlú Èkó. Ó jẹ́ Mùsùlùmí, ó sì wá láti Ìjẹ̀bú òdeÌpínlẹ̀ Ògùn. Ó gboyè nínú ìmò ìfowópámọ́ jáde ilé ẹ̀kọ́ Lagos State Polytechnic. Ó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos níbi tí ó tí gboyè nínú ìmọ̀ Sociology.[4]

Ìgbésí ayé rẹ̀

àtúnṣe

Folashade fẹ́ Razaq Okoya nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mọ́kànlélógún, ní àkókò tí ọkọ rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ ọdún mokandinlọ́gọ́ta.[5] Ó tí bí ọmọ mẹ́rin.[6] Folashade ní olùdásílẹ̀ ìdíje Folashade Okoya kids cup. Ní ọjọ́ kẹtàlélógún, oṣù kẹjọ ọdún 2014, ilé ẹ̀kọ́ gíga tí European American University fún ní ìwé ẹ̀rí nínú ìmò Business Management and Corporate Leadership[7]. Ó gbà àmì Inspiring Executive Woman of the Year Award ní oṣù kẹjọ ọdún 2018.[8]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Nigeria's Manufacturing Power Couple On The Future Of Manufacturing In Nigeria". Forbes Africa. Retrieved 26 February 2020. 
  2. "Shade Okoya's Rising Profile". Vanguard News. Retrieved 26 February 2020. 
  3. "Behold Stylish Female CEOs". Nation Online. Retrieved 26 February 2020. 
  4. "Folashade Okoya Speaks About Family, Marriage And Business". Channels Television. Retrieved 26 February 2020. 
  5. "ICYMI: Young, pretty wives of wealthy Nigerian businessmen, monarchs". Punch Nigeria. Retrieved 26 February 2020. 
  6. "I'm not a feminist, my husband is the head of our home - Shade Okoya". Vanguard Allure. Retrieved 26 February 2020. 
  7. "Billionaire's Wife Folashade Okoya receives Honorary Doctorate". Bella Naija. Retrieved 26 February 2020. 
  8. "Photos as Shade Okoya wins Inspiring Executive Woman of the Year Award in UK". Eagle Online. Retrieved 26 February 2020.