Shafi Edu
Olóṣèlú
Olóyè Shafi Lawal Edu (1911–2002), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí S.L. Edu,ni ó jẹ́ òṣùpá lágbo àwọn Ó lò kò wó àdàni ní ilẹ̀ Nàìjíríà, àti conservationist ọmọ bíbí ìlú Ẹ̀pẹ́, ní ìpínlẹ̀ Èkó. Òun ni ó dá Conservation Fund ilẹ̀ Nàìjíríà sílẹ̀ tí ó jẹ́ àjọ tí ó jẹ́ ti aládáni. Wọ́n bí Eru ní ìlú Ẹ̀pẹ́ sínú ẹbí ọ̀gbẹ́ni Lawani Edu; ẹni tí ó jẹ́ aláya púpọ̀ nígbà tí Iya rẹ̀ Raliatu jẹ́ ọmọ adarí kan nínú ẹ̀sìn Islam. [1] [2]
S. L. Edu | |
---|---|
Fáìlì:Shafi Edu, 1987.jpg Shafi Edu welcoming Prince Bernhard to Nigeria, 1987 | |
Western Region Commissioner for Health and Social Services | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Epe, Lagos State, Nigeria | Oṣù Kínní 7, 1911
Aláìsí | January 8, 2002 Ikoyi, Lagos, Nigeria | (ọmọ ọdún 91)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ìrìnkè-rindò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ láti Ilé Kéwú, ṣáájú kí ó tó wọ Ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Government Muslim ní ìlú Ẹ̀pẹ́. Ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ọdún 1927, tí ó sì padà ṣe ṣẹ́ olùkọ́ ní Ilé-ẹ̀kọ́ tí ó ti jáde.[1] [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Chief S.L Edu Research Grant". Nigerian Conservation Foundation. Archived from the original on 2019-12-29. Retrieved 2019-12-29.
- ↑ "NCF holds 16th S.L. Edu Memorial Lecture". Vanguard News. 2018-01-16. Retrieved 2019-12-29.
- ↑ "Your favorite newspapers and magazines.". PressReader.com. 2019-04-29. Retrieved 2019-12-29.