Shafy Bello tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ òṣèrébìnrin àti olórin. Orin kíkọ ni ó fi kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ níbi tí ó ti farahàn nínú orin Seyi Sodimu tí "Love Me Jeje" jẹ́ àkọ́lé rẹ̀ ni ọdún 1997.[1][2][3]

Shafy Bello
Àwòrán lati inu fiimu' Fishbone
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànShafy Bello-Akinrimisi
Iṣẹ́
  • òṣèrébìnrin,
  • olórin
Ìgbà iṣẹ́1990s – present
Àwọn ọmọ2

Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Ìlú America ni Shafy dàgbà sí tí ó sì ti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀. Àkọ́lé fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ ni Eti Keta tí ó jẹ́ fíìmù Yorùbá.[4] Ilé ọkọ ni Shafy wà pẹ̀lú ọmọ méjì.[5][6][7]

Ní ọdún 2012, ó ṣe Joanne Lawson nínú fíìmù àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Tinsel, ó sì ṣe Adesuwa nínú Taste of Love. [8] Láti ìgbà náà ni Shafy ti farahàn nínú fíìmù àgbéléwò Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì, díẹ̀ lára wọn ni; When Love Happens, Gbomo Gbomo Express àti Taste of Love.[9][10]

Ààtò àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Àdàkọ:Inc-film

  • Chief Daddy
  • From Lagos with Love
  • Iboju

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe
Year Award ceremony Prize Result Ref
2012 2012 Best of Nollywood Awards Best Lead Actress in an English Movie Wọ́n pèé [11]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Onuoha, Chris (2 August 2015). "There's sexiness in all I do – Shaffy Bello". Vanguard Newspaper. http://www.vanguardngr.com/2015/08/theres-sexiness-in-all-i-do-shaffy-bello/. Retrieved 1 June 2016. 
  2. "Shaffy Bello : Biography - Filmography - Awards". Flixanda. Archived from the original on 17 September 2021. Retrieved 2020-05-03. 
  3. "Check out Shaffy Bello & her kids". P.M. News. 2020-01-02. Retrieved 2020-05-03. 
  4. "‘Dating father and son doesn't mean I’m promiscuous’ -Taste of Love star, Shaffy Bello cries". Ecomium Magazine. 10 August 2015. http://encomium.ng/dating-father-and-son-doesnt-mean-im-promiscuous-taste-of-love-star-shaffy-bello-cries/. Retrieved 1 June 2016. 
  5. "I Would Have Divorced My Husband- Shaffy Bello". Naij. 14 December 2015. https://www.naij.com/666075-i-would-have-divorced-my-husband-nollywood-actress.html. Retrieved 1 June 2016. 
  6. "Shafy Bello biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. Retrieved 2020-05-03. 
  7. "Shaffy Bello: 7 things you probably didn’t know about the actress". Pulse Nigeria. 2017-10-09. Retrieved 2020-05-03. 
  8. Igwegbe, Fola (15 October 2012). "Meet Tinsel's cougar". Africa Magic. http://africamagic.dstv.com/2012/10/15/meet-tinsels-cougar/. Retrieved 1 June 2016. 
  9. Ekpo, Nathan Nathaniel (14 August 2015). "I'm not a prostitute, I only interpret role...Actress, Shaffy Bello". Nigeria Films. http://www.nigeriafilms.com/news/35074/8/im-not-a-prostitute-i-only-interpret-roleactress-s.html. Retrieved 1 June 2016. 
  10. "Shaffy Bello: Five Must-Know Facts". Heavyng.Com. 2019-12-09. Retrieved 2020-05-03. 
  11. Ehi James, Osaremen (10 September 2012). "Tonto Dikeh, Funke Akindele Others Make BON Award nominees' list". Nigeria Films. Retrieved 1 June 2016.