Ìjẹ́ẹ̀rí
(Àtúnjúwe láti Shahada)
Shahada tabi ìjẹ́ẹ̀rí (Arabic: الشهادة aš-šahāda audio (ìrànwọ́·ìkéde)) (lati oro-ise [] error: {{lang}}: no text (help) šahida, "o jeri"), tumo si "lati mo ati gbagbo laisi ifura, bi jijeri"; o je ikan ninu awon opo marun islam. Shahada ni ike igbagbo ninu okan Allahu ta'âlâ ati igba Muhammad gege bi ojise Olorun. Ike yi ni pe:
- lâ ilâha illallâh, Muḥammadur rasûlullâh (ni Larubawa)
- Ko si olorun miran afi Olorun, Muhammad si ni Ojise Olorun (ni Yoruba)
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |