Shahid Azmi

Agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè India

Shahid Azmi (1977 – 11 February 2010) jẹ́ adájọ́ India àti àjàfẹ́tọ̀ọmọnìyàn .

Shahid Azmi
Fáìlì:Shahid Azmi.jpg
Shahid Azmi
Ọjọ́ìbíShahid Azmi
1977
Deonar, Mumbai, India
Aláìsí11 February 2010 (aged 32)
Mumbai
Cause of deathAssassination
Orílẹ̀-èdèIndian
Iṣẹ́

Wọn fi ẹ̀sùn kan Azmi ni ìgbà tó wà lọ́mọdé ni ọdún1992, ní ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dògún,wọn my fún jàgídíjàgọn ní ọdún 1992 ní ìgbà ìjà Bombay riots. Wọ́n dáa silẹ gẹ́gẹ́ bíi ọmọ kékeré tí kò ì tíì tọ́ lábẹ́ òfin láti lọ sí ẹ̀wọ̀n, àti pé kò sí ẹ̀rí tó gbàmùṣè láti takò ó. Gẹ́gẹ́ bíi ọdọ kékeré, agbófinró tún mú ú,ní ìgbà yìí lábẹ́ òfin Terrorist and Disruptive Activities (Prevention) Act, fún gbígbèrò lòdì sì orílẹ̀ èdè. Ó lo ọdún méje ní ọgbà ẹ̀wọ̀n, Delhi's Tihar Jail.[1] nínú ẹ̀wọ̀n ni ó ti ní ìwúrí láti padà sí ilé ẹ̀kọ́, nígbà tí wọ́n fi máa dá a sílẹ̀, ó ti ní kàwé gboyè àkọ́kọ́ ni ile iwe gíga nínú ẹ̀kọ́ nípa òfin. Ní ọdún 2003, ó bẹ̀rẹ̀ si ni gbẹjọ́rò fún àwọn ọ̀daràn ní Mumbai. Ó fẹ́ẹ̀ lè jẹ gbogbo ẹjọ́ tí ó mójútó ni ìgbà náà ni ó nìsẹ pẹlú àwọn tí wọ́n fi ẹ̀sùn jàgídíjàgọn lọ̀, tí òun sì gbàgbọ́ pé wọ́n kàn fi wọ́n ṣe ẹran ìyá ni. who he believed had been jailed as (scapegoats). Àwọn agbanipa mẹrin ni wọ́n yin ní ìbọn nínú ibi iṣẹ́ rẹ̀ ní Kurla, Mumbai ni ọjọ́ kankànlá ọdún 2010 ní ẹni ọdún méjìlélọ́gbọ̀n.[2][3]

Shahid Azmi jẹ́ ọmọ ẹ̀gbọ́n Abu Asim Azmi, olóṣèlú Samajwadi Party politician àti ọmọ ẹgbẹ́ Maharashtra Legislative Assembly láti agbègbè GovandiMumbai.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀ àti ìgbé ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Azmi, ó sì dàgbàà sì Deonar suburb of Mumbai,sí inú ẹbí Mùsùlùmí tí wọ́n ṣẹ̀ láti Azamgarh, Uttar Pradesh. Òun ni ọmọkùnrin kẹta nínú àwọn márùn-ún.[4] ọkàn nínù àwọn arákùnrin rẹ̀, Khalid Azmi,náà jẹ́ algbáwí ní Mumbai.[5] Shahid Azmi fẹ́ Maryam ti àwọn ìlúmọ̀ọ́ká àwọn Assamese,ṣùgbọ́n ó padà kọ̀ ọ́ sílẹ̀

Ẹ̀ṢẸ̀ ÀTI ÌTÌMỌ́LÉ

àtúnṣe

Ní ọmọ ọdún mẹ́rìnlá ,agbófinró Mumbai gbé Azmi fún pé ó lọwọ́ sí ìjà ọdún 1992 Mumbai communal riots. Nítorí kòì tíì tó ẹni tí ó yẹ kó lọ sí ẹ̀wọ̀n lábẹ́ òfin, wọ́n dá a sílẹ̀ láì san ohun ìtanràn kankan,kò dẹ̀ tún ṣe ẹ̀wọ̀n. Làípẹ́ sì èyí, ó sọdá sí Pakistan-occupied Kashmir, níbi tí ó ti lo ìgbà díẹ̀ ni ọgbà àwọn ọmọ ológun, ṣùgbọ́n ó padà lẹ́yìn ìgbà díẹ̀,gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ níbi ìfọ̀rọ̀wánulẹ́nuwò tí ó ṣe pẹ̀lú The Times of India, "mo ti rí agbófinró tí wọn pa àwọn ènìyàn láti agbegbe mi. Mo rí tí wọn pa ẹ̀jẹ̀ tútù. Èyí ló ru ìbínú mi sókè tí kì fi darapọ̀ mọ́ àti dènà irú nkan bẹ́ẹ̀."[6] NÍ oṣù kẹfà ọdún1994, wọn gbé lábẹ́ ìwà jàgídíjàgọn Terrorist and Disruptive Activities (ìdáàbòbò) Act (ẹgbẹ́ náà kò sí ), fún ẹ̀sùn pípa àwọn olóṣèlú kàn-àn-kan àti Shiv Sena leader, Bal Thackeray, wọ́n sì dá a lẹ́jọ́ ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún, sugbon ni ọdún yẹn náà ni ilé ẹjọ́ gíga dá a sílẹ̀ láì ní ẹ̀sùn kan kan, ju gbogbo ẹ̀ lọ, ó lo ọdún méje ní ọgbà ẹ̀wọ̀n Tihar ni Dehil

Ní àkókò tí ó wà ní ọgbà ẹ̀wọ̀n Tihar, ó bẹ̀rẹ̀ ilé ìwé gírámà, lẹ́yìn èyí ni ó tẹ̀sìwàjù nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ìwé gíga, ó kọ́ nípa ìwé kíkọ, lẹ́yìn tí wọn dá a sílẹ̀ ni ilé ẹjọ́ láì san ìtanràn rárá, ni ó lọ kọ́ nípa ẹ̀kọ́ òfin (LLM) ní Mumbai.[6][7][8]

Lẹ́yìn tí kàwé gboyè àkọ́kọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga,ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú agbẹjọ́rò Majeed Memon fún oṣù díẹ̀,[9] Kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbẹjọ́rò ní 2003. Làípẹ́ ó bẹ̀rẹ̀ sí ní mú àwọn ẹjọ́ àwọn Mùsùlùmí tí wọ́n fi sì abẹ́ Prevention of Terrorism Act, 2002 (POTA). Ọ̀pọ̀ ọ̀pọ̀ nínú àwọn ẹjọ́ yí ni wọn ń ṣe ní àìsówo pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ NGOs, bíi Jamiat Ulama-e-Hind.[7]Àṣeyọrí pàtàkì gẹ́gẹ́ bíi agbẹjọ́rò His first major success as a defence lawyer came in the 2002 Ghatkopar bus bombing case, when Arif Paanwala, who was arrested under Prevention of Terrorism Act (POTA) and was named the prime accused, was acquitted along with eight others, due to lack of evidence, by the court; this eventually led to the law being repealed.[10]

Azmi then had represented the accused in the 7/11 Mumbai local train blasts, the 2006 Aurangabad arms haul, the 2006 Malegaon blasts case.[2][7] Though the High Court had rejected his application challenging the use of the Maharashtra Control of Organised Crime Act (MCOCA) in these alleged terrorism cases and asked for stay, in February 2008, the Supreme Court of India stayed the three trials.[10] In July 2008, Azmi filed a petition in the High Court alleging that the accused in the 7/11 Mumbai blasts, then lodged in the Arthur Road Jail, were being tortured. Responding to the petition, the court ordered an inquiry in the case, and the allegations were found to be true.[10] In his brief career of seven years, he secured 17 acquittals in court.[11]

It was while he was defending Faheem Ansari in the 26/11 attacks case that he was killed. Ansari was acquitted of all the charges by the Supreme Court of India due to lack of evidence on 19 August 2012.[9]

He was killed on 11 February 2010 in his office at Taxi Men colony in Kurla, when four gunmen entered his office and shot two bullets, point blank and fled. Though he was taken to Rajawadi Hospital in Ghatkopar, he was soon declared dead.[2][12][13]

Murder case

àtúnṣe

In February 2010, member of the Bharat Nepali gang, Devendra Babu Jagtap alias JD, Pintoo Deoram Dagale, Vinod Yashwant Vichare and Hasmukh Solanki, were arrested by the police under MCOCA.[5] The police however did not conduct any forensic of the murder weapons and claimed that the murder was "solved" by the arrest of the accused.[12]

Couple of months later, in June 2010, Inder Singh, who was Azmi's peon at the time and the lone eyewitness of the assassination, lodged a complaint alleging receiving a threatening call, which was later traced to Gujarat.[14] On 20 January 2011, MCOCA court dropped the MCOCA charges levelled against the accused in the police chargesheet as it found no evidence suggesting "pecuniary gains were made in the crime, a mandatory aspect for MCOCA charges."[15]

Then in April 2011, while the accused were in a sessions court at Kala Ghoda, for a hearing the police caught a man named Munna reportedly of Navlekar gang, with a weapon and live cartridges in the court premises, who had come allegedly to free the accused.[5]

On 23 July 2012, the Bombay High Court granted bail to one of the accused, Vinod Vichare, against a personal bond of Rs 50,000 stating he was not "shown to be present" during the assassination. Vichare had already spent two years in jail, ever since he was held for the possession of one of the four revolvers given to Bharat Nepali.[16]

Accusations on the Intelligence Bureau

àtúnṣe

In a 2007 interview with Rediff News Correspondent Sheela Bhatt, Azmi accused the police of staging an encounter at Antop Hill where a Pakistani was killed, because, that area was isolated and "terrorists always hide in places where you find a lot of other people".[17] He further accused the Intelligence Bureau of perpetrating the 2006 Mumbai train bombings, which are otherwise believed to be the work of Lashkar-e-Taiba and Students Islamic Movement of India. When asked as to why Intelligence Bureau would indulge in such acts against national interests, he said it was to stereotype Muslims and lobby for stringent laws.[17]

àtúnṣe

A biographical film based on his life titled, Shahid (2013) starring Rajkummar Rao, was directed by Hansal Mehta and produced by Anurag Kashyap. The film had its world premiere at the 2012 Toronto International Film Festival's 'City to City' programme in September 2013 and was released on 18 October 2013 in India.[7] The film has a scene in which Mr Azmi's face is blackened by assailants outside the court room. This, admittedly was, just a re-enactment of an incident in the director's own life as against that of Azmi.[1] Furthermore, several petitions filed by Azmi were combined into a single case for dramatic effect in the film.[1]

Gujarat Files, a 2016 book by Rana Ayyub is dedicated to Shahid Azmi along with advocate and activist Mukul Sinha.

See also

àtúnṣe

References

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 "Film remembers Indian lawyer Shahid Azmi as symbol of hope". BBC. 28 September 2012. https://www.bbc.co.uk/news/world-asia-india-19595663. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "26/11 accused Fahim Ansari's lawyer Shahid Azmi shot dead". The Times of India. 11 February 2010. Archived from the original on 25 September 2013. https://web.archive.org/web/20130925131620/http://articles.timesofindia.indiatimes.com/2010-02-11/india/28127692_1_fahim-ansari-assailants-shahid-azmi. 
  3. Ajit Sahi (27 February 2010). "A Grain in My Empty Bowl: A crusader for justice is silenced. Actually not ..". Tehelka Magazine, Vol 7, Issue 08. Archived from the original on 2 April 2010. Retrieved 20 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Shivam Vij (10 February 2011). "Remembering Shahid Azmi, the Shaheed: Mahtab Alam". Kafila. Archived from the original on 9 February 2021. Retrieved 22 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. 5.0 5.1 5.2 "Man on mission to free Shahid Azmi killer from court arrested". DNA. 9 April 2011. http://www.dnaindia.com/mumbai/report_man-on-mission-to-free-shahid-azmi-killer-from-court-arrested_1529906. 
  6. 6.0 6.1 "Lawyer who 'piqued' Salian was once pursued by law". The Times of India. 15 August 2004. Archived from the original on 27 February 2013. https://web.archive.org/web/20130227001919/http://articles.timesofindia.indiatimes.com/2004-08-15/mumbai/27156136_1_shahid-azmi-tada-remand-home. 
  7. 7.0 7.1 7.2 7.3 "The 'unlikely' lawyer as an unlikely hero". Indian Express. 9 August 2012. http://www.indianexpress.com/news/the-unlikely-lawyer-as-an-unlikely-hero/985769/0. Retrieved 21 August 2012. "A movie based on the lawyer and human rights activist.." 
  8. "Shahid Azmi never tried to hide his past as Tada detainee". DNA. 12 February 2010. http://www.dnaindia.com/mumbai/report_shahid-azmi-never-tried-to-hide-his-past-as-tada-detainee_1346670. 
  9. 9.0 9.1 "The lawyer who courted death". Mint. 13 September 2012. http://www.livemint.com/Leisure/ryxborlNOcg3cP0Bh7GSDM/The-lawyer-who-courted-death.html?facet=print. 
  10. 10.0 10.1 10.2 "Shahid Azmi: Short career, long-lasting impact". DNA. 13 February 2010. http://www.dnaindia.com/mumbai/report_shahid-azmi-short-career-long-lasting-impact_1347133. 
  11. "Film remembers Indian lawyer Shahid Azmi as symbol of hope". BBC News. 28 September 2012. https://www.bbc.co.uk/news/world-asia-india-19595663. "a murdered Indian human rights lawyer.." 
  12. 12.0 12.1 Rana Ayyub (2 March 2010). "A murder riddled with holes: The irony is that slain lawyer Shahid Azmi came to fame exposing police lapses". Tehelka. Archived from the original on 7 October 2011. Retrieved 20 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  13. Shahid Azmi dead Archived 9 February 2021 at the Wayback Machine. NDTV.
  14. "Witness in Shahid Azmi murder case gets threat". The Times of India. 11 June 2010. Archived from the original on 4 January 2013. https://archive.today/20130104004847/http://articles.timesofindia.indiatimes.com/2010-06-11/mumbai/28276336_1_shahid-azmi-murder-case-police-protection-key-witness. 
  15. "Azmi murder: Court drops MCOCA charges against four". Indian Express. 22 January 2011. http://www.indianexpress.com/news/azmi-murder--court-drops-mcoca-charges-against-four/740802/. 
  16. "Accused in Shahid Azmi murder case gets bail". DNA. 23 July 2012. Archived from the original on 9 February 2021. Retrieved 22 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  17. 17.0 17.1 "Introspect why the educated Muslim is taking to violence". http://www.rediff.com/news/2007/jul/27inter.htm. 
àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control