Shaleen Surtie-Richards
Shaleen Surtie-Richards (bíi ni ọjọ́ keje, oṣù karùn-ún, ọdún 1955)[1] jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Fiela se Kind ni ọdún 1988 àti Egoli: Place of Gold.
Shaleen Surtie-Richards | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Kàrún 1955 Upington, Cape Province, South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Iṣẹ́ | Actress, talk show host |
Ìgbà iṣẹ́ | 1974-present |
Gbajúmọ̀ fún | Fiela se kind, Egoli: Place of Gold, Supersterre |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bíi Shaleen sí ìlú Upingtong ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Bàbá rẹ̀ jẹ́ olùdarí ilé ẹ̀kọ́, ìyá rẹ sì ju olùkọ́.[2][3] Surtie-Richards jẹ́ olùkọ́ fún àwọn ọmọdé láti ọdún 1974 di ọdún 1984. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ni ọdún 1984.
Iṣẹ́
àtúnṣeSurtie-Richard ṣe adájọ́ fún ètò Supersterre láti ọdún 2006 di ọdún 2010.
Fíìmù
àtúnṣe- Fiela se Kind (1988)
- Mama Jack (2005)
- Egoli: Afrikaners Is Plesierig (2010)
- Knysna (2014)
- Treurgrond (2015)
- Twee Grade van Moord (2016)
- Vaselinetjie (2017)
Eré orí Telefiisonu
àtúnṣe- Egoli: Place of Gold
- 7de Laan
- Villa Rosa
- Generations
Eré orí itage
àtúnṣeÀwọn àmì ẹyẹ tó ti gbà
àtúnṣeSurtie-Richard tí gbà àmì ẹ̀yẹ tó lé ní ogójì. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré tó dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Fleur du Cap Theatre Awards fún ipá Hester tí ó kó nínú eré Hallo en Koebaai (Hello and Goodbye). Ní ọdún 2009, ó gbà ẹ̀bùn míràn láti ọ̀dọ̀ Fleur du Cap Awards fún ipá tí ó kó nínú eré Shirley Valentine ni ọdún 2008. Ní ọdún 2018, ó gbà ẹ̀bùn eléré tó gbajúmọ̀ láti ọ̀dọ̀ Herrie Prize níbi ayẹyẹ Klein Karoo Arts Festival.[8] Ní ọdún 2014, ó gbà ẹ̀bùn fún akitiyan rẹ tí ó tí kó nínú àwọn eré bíi Egoli: Place of Gold, Generations, and 7de Laan.[9] Wọn yàán kalẹ̀ fún ẹ̀bùn òṣèré tó tayọ julọ ni ọdún 2014.[10] O gba ebun láti ọ̀dọ̀ Naledi Theater Awards ni ọdún 2015.[11]
Àwọn itokasi
àtúnṣe- ↑ "Shaleen Surtie-Richards". TVSA: Television South Africa. TVSA. Retrieved 5 December 2016.
- ↑ De Villiers, Basheerah (12 December 2014). "'What you see is what you get; I cannot be pretentious,' says Shaleen Surtie-Richards". The South African. http://www.thesouthafrican.com/what-you-see-is-what-you-get-i-cannot-be-pretentious-says-shaleen-surtie-richards/. Retrieved 5 December 2016.
- ↑ Cohen, Robyn (14 March 2010). "Veteran of the Fleur du Caps; Shaleen Surtie-Richards is set to be a highlight of the awards at which she made history 26 years ago". Argus Weekend (South Africa).
- ↑ "Drama, farce centre stage at fest". The Pretoria News. 4 August 2015.
- ↑ Cavernelis, Dennis (22 April 2008). "Bye's Yellowman wins best KKNK production". Cape Times (Independent Online (South Africa)).
- ↑ "Diverse Drama at Suidoosterfees". The Argus (Cape Town) (Independent Online (South Africa)). 16 April 2016.
- ↑ Doudai, Naomi (31 August 1989). "Edinburgh Takes the Stage". Jerusalem Post.
- ↑ Cavernelis, Dennis (22 April 2008). "Bye's Yellowman wins best KKNK production". Cape Times (Independent Online (South Africa)).
- ↑ "Isibaya wins big at Royalty Soapie Awards". Channel24 (24.com). 10 March 2014. http://www.channel24.co.za/TV/News/Isibaya-wins-big-at-Royalty-Soapie-Awards-20140310. Retrieved 5 December 2016.
- ↑ "Nominees announced for the Royalty Soapie Awards". Channel24 (24.com). 18 February 2014. http://www.channel24.co.za/TV/News/Nominees-announced-for-the-Royalty-Soapie-Awards-20140218. Retrieved 5 December 2016.
- ↑ "Marikana the Musical triumphs with six Naledi Theatre Awards". News24 (24.com). 15 April 2015. http://www.news24.com/Archives/City-Press/Marikana-the-Musical-triumphs-with-six-Naledi-Theatre-Awards-20150430. Retrieved 5 December 2016.