Sheikh Hasina

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Bangladesh

Sheikh Hasina Wazed (Bẹ̀ngálì: শেখ হাসিনা ওয়াজেদ Shekh Hasina Oajed) (ojoibi September 28, 1947) je oloselu omo ile Bangladesh, ohun si ni Alakoso agba ile Bangladesh lati 6 January, 2009.

Sheikh Hasina Wajed
শেখ হাসিনা ওয়াজেদ
Alakoso Agba ile Bangladeshi
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
6 January 2009
ÀàrẹIajuddin Ahmed
Zillur Rahman
AsíwájúFakhruddin Ahmed (Acting)
In office
23 June 1996 – 15 July 2001
ÀàrẹShahabuddin Ahmed
AsíwájúHabibur Rahman (Acting)
Arọ́pòLatifur Rahman (Acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹ̀sán 1947 (1947-09-28) (ọmọ ọdún 77)
Gopalganj, East Pakistan (now Bangladesh)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúBangladesh Awami League Grand Alliance
(Àwọn) olólùfẹ́M. A. Wazed Miah (d. 2009)
Àwọn ọmọSajeeb Wazed Joy & Saima Wazed Putul