Sheila Okai
Sheila Okai tí a bí ní ọjọ kẹrìnlá osù kejì ọdún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ará ilẹ̀ Ghana kan tí ó ń ṣeré ní ipò agbedeméjì àti iwájú. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède Ghana . Ó wà lára àwọn tí o kópa ní bi FIFA Women's World Cup ti ọdún 1999 [1] àti ní FIFA World Cup Women's World Cup ti ọdún 2007 . Lórí ìpele ẹgbẹ́, ó ṣeré fún Ghatel Ladies ní Ghana. [2]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | ọjọ kẹrìnlá osù kejì ọdún 1979 | ||
Playing position | ipò agbedeméjì àti iwájú | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ghatel Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana | 30 | (5) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |