Shelley Luther
Shelley Luther | |
---|---|
Luther speaks at the 2024 Young Americans for Liberty national convention | |
Member-elect of the Texas House of Representatives from the 62nd district | |
Taking office January 14, 2025 | |
Succeeding | Reggie Smith |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kàrún 1973 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Republican |
Àwọn ọmọ | 2 |
Profession | Salon owner · politician |
Shelley Luther (wọ́n bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù Èbìbí, 1973)[1] jẹ́ olóṣèlú ati oní ilé ìṣe orí lóge ní Amẹ́ríkà tí ó ṣì tún jẹ́ ará ọmọ ilẹ̀ ìgbìmò aṣòfin ni Texas láti dísíríìtì kejì lé ní ọgọ́ta tí wọ́n dìbò Yàn.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Garcia, Nic; Jaramillo, Cassandra; Jimenez, Jesus (May 6, 2020). "Meet the Dallas salon owner whose decision to reopen put her in the middle of a national debate". The Dallas Morning News. https://www.dallasnews.com/news/politics/2020/05/06/meet-the-dallas-salon-owner-whose-rule-breaking-put-her-in-the-middle-of-a-national-debate/.