Shirley Chisholm
Olóṣèlú
Shirley Anita St. Hill Chisholm (November 30, 1924 – January 1, 2005) je oloselu, oluko ati olukowe ara Amerika.[3] O je omo-egbe Ile Asofin, nibi to ti soju fun Agbegbe Ile Asofin 12k New York fun igba emeje lati 1969 de 1983. Ni 1968, o di obinrin alawodudu akoko to je didiboyan si Ile Asofin Amerika.[4]
Shirley Chisholm | |
---|---|
Member of the U.S. House of Representatives from New York's 12th district | |
In office January 3, 1969 – January 3, 1983 | |
Asíwájú | Edna F. Kelly |
Arọ́pò | Major R. Owens |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Shirley Chisholm Oṣù Kọkànlá 30, 1924 Richmond, Virginia[1] |
Aláìsí | January 1, 2005 Ormond Beach, Florida[2] | (ọmọ ọdún 80)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
{{{blank1}}} | 1) Conrad Chisholm (divorced) 2) Arthur Hardwick Jr. (widowed) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedbirth
- ↑ Barron, James (3 January 2005). "Shirley Chisholm, 'Unbossed' Pioneer in Congress, Is Dead at 80". The New York Times. http://www.nytimes.com/2005/01/03/obituaries/03chisholm.html. Retrieved 24 December 2010.
- ↑ PBS P.O.V. documentary. "Chisholm '72: Unbought & Unbossed"
- ↑ Freeman, Jo (February 2005). "Shirley Chisholm's 1972 Presidential Campaign". University of Illinois at Chicago Women's History Project. http://www.uic.edu/orgs/cwluherstory/jofreeman/polhistory/chisholm.htm.