Shola Adewusi
Shola Adewusi gbọ́ (tí a bí ní ọdún 1963) jẹ́ òṣèrébìnrin Òṣerébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Àpẹrẹ awọn iṣẹ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ìmóhùn máwòrán ni Little Miss Jocelyn, BBC comedy sketch show series tí Jocelyn Jee Esien kọ, Òun ni ó ń kó ipa Auntie Olu lọ́wọ́ lọ́wọ́ nínú fíìmù CBS; Bob Hearts Abishola