Shola Akinlade
Ṣọlá Akínlàdé jẹ́ onímọ̀ nípa software ati ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Paystack.[1][2]
Ètò ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeṢọlá lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama St. Gregory's College tí ó sì jáde ìwé mẹ́wá jáde. Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Babcock University níbi tí ó ti lọ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ Kọ̀mpútà tí ó sì jáde níbẹ̀ ní ọdún 2006.[3]
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní ilé-iṣẹ́ Heineken níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí alábójútó database ilé-iṣẹ́ náà, ṣáájú kí ó tó lọ ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn oríṣiríṣi ilé ìfowó-pamọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2] Ní ọdún 2016, Sọlá ati Ezra dá ilé-iṣẹ́ Paystack sílẹ̀.[1][4]
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Nigeria: “The hard work is still in front of us” - Paystack CEO". The Africa Report.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-23. Retrieved 2021-06-14.
- ↑ 2.0 2.1 Can more entrepreneurs shake up fintech in Nigeria? - CNN Video, retrieved 2021-06-14
- ↑ "Meet Sola Akinlade, co-founder of Nigeria’s foremost payment platform Paystack". Nairametrics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-08. Retrieved 2021-06-14.
- ↑ Nsehe, Mfonobong. "Nigerian Fintech Startup Paystack Raises $1.3 Million". Forbes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-14.