Shure Demise Ware tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kìíní, ọdún 1996 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa nínú eré-ìdárayá eré-sísá ní orílẹ̀-èdè Ethopia, tó sì ti kópa nínú ìdíje lóríṣiríṣi.[1]

Àṣeyọrí

àtúnṣe

Ní ọdún 2015, Demise kópa nínú Marathon ti Dubai tó sì parí pẹ̀lú ipò kẹrin[2]. Ní ọdún 2015, Demise kópa nínú Marathon ti ilẹ̀ Boston tó sì parí pẹ̀lú ipò kẹjọ[3]. Ní ọdún 2019, Demise kópa nínú Marathon ti àwọn obìnrin ní ìdíje àgbáyé lórí eré sísá tó wáyé ní Doha, Qatar[4].

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Shure DEMISE - Profile". worldathletics.org. 1996-01-01. Retrieved 2023-04-10. 
  2. Dubai Marathon
  3. Boston Marathon
  4. Women Marathon