Ogun Abẹ́lé Siẹrra Lẹ́ónè
(Àtúnjúwe láti Sierra Leone Civil War)
The Sierra Leone Civil War bere ni 23 March 1991 nigbati Revolutionary United Front (RUF), pelu itileyin latowo awon ajagun pataki National Patriotic Front of Liberia (NPFL) ti Charles Taylor, fe fi tipatipa leJoseph Momoh to je aare orile-ede Sierra Leone kuro lori ijoba, eyi fa ogun to pa awon eniyan to to 50,000.[1]
Sierra Leone Civil War | |||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|
Map of Sierra Leone | |||||||
| |||||||
Àwọn agbógun tira wọn | |||||||
Sierra Leone Kamajors Executive Outcomes (South Africa-based mercenary group) Nigerian-led ECOMOG forces United Nations Mission to Sierra Leone United Kingdom |
RUF NPFL AFRC West Side Boys | ||||||
Àwọn apàṣẹ | |||||||
Ahmad Tejan Kabbah Samuel Hinga Norman Valentine Strasser Solomon Musa David J. Richards Tony Blair |
Foday Sankoh Johnny Paul Koroma Sam Bockarie Foday Kallay Charles Taylor | ||||||
Òfò àti ìfarapa | |||||||
Upwards of 50,000 Sierra Leoneans[1] 2.5 million displaced internally and externally[1] |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |