Simu Liu ( /ˈsm ˈljuː/ SEE-moo-_-LEE-yoo;[2] Àdàkọ:Zh; tí a bí ní ọjọ́ kandínlógún oṣù Kerin ọdún 1989) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Kanada. Ó gbajúmọ̀ fún kíkọ́ ipa Shang-Chi nínú fíìmù Marvel Cinematic Universe, Shang-Chi and the Legend of the Ten Rings tí ó jáde ní ọdún 2021. Ó tún kó ipa gẹ́gẹ́ bi Jung Kim nínú fíìmù CBC Television Kim's Convenience[3] ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ ACTRA Award àti Canadian Screen Awards fún ipa rẹ̀ nínú Blood and Water.[4]

Simu Liu
Simu Liu speaking at the San Diego Comic-Con International in 2019
Liu ní ọdún 2019
Orúkọ àbísọ刘思慕
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kẹrin 1989 (1989-04-19) (ọmọ ọdún 35)
Harbin, Heilongjiang, China
Orílẹ̀-èdèCanadian[1]
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Western Ontario (HBA)
Iṣẹ́
  • Actor
  • stuntman
  • author
Ìgbà iṣẹ́2012–present
AwardsFull list
Simu Liu
Traditional Chinese 劉思慕
Simplified Chinese 刘思慕

Ní ọdún 2022, Liu ko ìwé We Were Dreamers,[5] Time sì pè é ní ará àwọn òṣèré ọgọ́rùn-ún tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní àgbáyé.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àdàkọ:Cite tweet
  2. Àdàkọ:Cite tweet
  3. "Kim's Convenience – CBC Media Centre". Canadian Broadcasting Corporation. Retrieved 29 July 2016. 
  4. "Simu Liu – Academy.ca". Academy.ca. 8 January 2017. Retrieved 22 January 2017. 
  5. "From immigrant to superhero: Simu Liu tells his own origin story in memoir 'We Were Dreamers'". www.wbur.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-21. 
  6. "Simu Liu: The 100 Most Influential People of 2022" (in en). Time. 23 May 2022. https://time.com/collection/100-most-influential-people-2022/6177789/simu-liu/. Retrieved 2022-12-21.