Sìnáì
(Àtúnjúwe láti Sinai Peninsula)
Sinai tabi Peninsula Sinai; Lárúbáwá: سيناء sīnā'a; Hebrew סיני) je peninsula onigunmeta kan ni Egypt to je be 60,000 km2 (23,000 sq mi). O dubule si arin Omiokun Meditareani si ariwa, ati Omiokun Pupa si guusu, be sini ohun nikan ni apa ile Egypti to budo si Asia niyato si Africa. Lapapo mo oruko onibise re, awon ara Egypti tun pe ibe ni "Ile Fayrous" ("Land of Fayrouz"), toduro lori oro ede Egypti Ayejoun "Dumafkat", to ni itumo kanna. Peninsula na je pinpin si ile-gomina Egypti meji, o si ni olugbe bi egbegberun 1.3 awon eniyan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |