Sinke Biyadgilgn
Sinke Dessie Biyadgilgn ni a bini ọdun 1995 jẹ Akọṣẹmọṣẹ elere sisa lóbinrin ta bisi órilẹ ede Ethiopia to sin gbe ni Washington, D .C[1].
Àṣèyọri
àtúnṣeNi 2018, Sinke kopa ninu Marathon ti ibeji pẹlu wakati 2:33:04 nibi to ti gba ẹbun owo ti $7,500[2][3]. Ni ọdun 2016, Sinke kopa ninu ere sisa ti mile maarun pẹlu wakati 26:51[4].