Sínńtààsì Èdè Aafíríka

(Àtúnjúwe láti Sintaasi Ede Aafirika)

AKANDE TITILAYO C.

Sintaasi ede Aafirika

SYNTAX- JOHN R. WATTERS.

John R. Watters túmọ̀ sínńtààsì sí bí ìró àti ọ̀rọ̀ se ń so papọ̀ di gbólóhùn, àti bí àwọn ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan se hun ara wọn papọ̀ ní ìpele, ìpele di gbólóhùn.

Gbogbo èdè ni wọ́n ní ju ọ̀nà kan lọ ti wọn ń gba hun ọ̀rọ̀ wọn. tí a bá ń kọ nípa èdè kan, àfojúsùn wa ni láti se àfìwé ìdí tí ìhun wọn fi pé orísìírísìí. Ní ilẹ̀ Afirika, ó fẹ́ẹ̀ jẹ́ pé gbogbo èdè ni wọn ń lo Olùwà, àbò àti ọ̀rọ̀ ìṣe.

A tún máa ń lo “less common word orders” nínú gbogbo èdè, láti sèdá gbólóhùn àyísódì.

(SENTENCES WITH SINGLE CLAUSES) GBÓLÓHÙN ALÁWẸ̀ KAN.

Ètò ọ̀rọ̀ (Word categories) Àwọn ọ̀rọ̀ tí a máa ń tò pọ̀ di gbólóhùn ni OR, IS, Apọnle, Eyan àti Atókùn. Iwájú ọ̀rọ̀ orúkọ ni atọ́kùn máa ń wà Post Position máa ń wa lẹ́yìn ọ̀rọ̀ orúkọ.

Nínú èdè Afirika, OR ati Is se iyebíye. Àwọn èdè Africa máa ń lo Is dáadáa ju àwọn èdè Gẹ̀ẹ́sì àti èdè àwọn European. Fún àpẹẹrẹ:

Aghem, Bantu, Benu-Congo, Niger-Congo

-(i)	fi - baףּà – The bird is red. 

Ọ̀rọ̀ Ise ni wọ́n lo red fún nínú gbólóhùn yìí.

- Ngiti, Lendu, Central Sudanic, Nilo-Sohare

-(ii) mà m-àndi we are ill

Ẹ̀wẹ̀, a lè lo ọrọ ìṣe ní ibi tí àwọn elédè Gẹ̀ẹ́sì bá ti ń lo àpọ́nlé (e.g. frequently, not yet, still, again) ati ọ̀rọ̀ àsopọ̀ (Conjunction) e.g. and, their’

- Yorùbá, Defoid, Benue – Congo, Niger- Congo

(i) Ó tún ń lọ. He is going again.

- Ejapham, Ekoid Bantu, benue-Congo – Niger-Congo

(ii) à-njánà à-Chòr-á She is still talking


Àwọn Èdè Africa kò ní Atókà púpọ̀ bí Europeans. Èdè Afíríka jẹ́ èdè olóhùn, èyí ni a sì fi máa ń dá wọn mọ̀ yàtọ̀.

- Babungo, Bantu, Benu- Congo ati Niger-Congo

(i) ףּwá báy làa bàà He was very, very red

(ii) ףּwá nyiףּ máa tátátә He ran quickly and Continuosly


Gbólóhùn oní pọ́nónna (Simple Sentence)

Àwọn wọ̀nyí: Subject (s) verb (v) obuject (o) ni a máa ń lò láti sàlàyé gbólóhùn

Svo ni o gbajúmọ̀ ní ilẹ̀ Afroasiatic àti ní Niger-Congo yàtọ̀ sí Mande, Senufo àti Ijo, Ní ilè Khoisan – Khoe náà yàtọ̀ fún àpẹẹrẹ:

Hausa, Chadic, Afroasiatic

(i) S V O

Obdun yaa ci na amaaa

Swahili, Bantu, Benu – Congo, Niger-Congo

(ii) S V O

Halima a-na-pika ugali

Halima is cooking porridge

Nínú àwọn èdè wọ̀nyí:

- Bari, Eastern Nilotic, Nilo – Saharan, S V O Adv ló gbajúmọ̀.

(iii) S V O Adv

      teleme        a kop       kene    ‘de’ de 

‘The monkey Caught the branch quickly

Ìkejì tí ó tùn gbajúmọ̀ ní ilẹ̀ Afirika ni SOV. A lè rí i ní Ethio-Semitic, Cushitic àti Omotic láàrin Afroasiatic ní senufo : Bí àpẹẹrẹ:

(i) Silt’e, Ethio – Semitic, Afroasiatic

S O V

isaam ciitañe gilgil Ceeñeet


(ii)	Supyire, Senufo, Gur, Niger-Congo 

S O V

Kile ù kùni pwọ

‘May God sweep the path.

(iii) Aiki, Maban, Nilo-Saharan

S O V

gòףּ yàףּ sám tare

‘The farmer occupies a fiertile plot.

Ìkẹta ni VSO, òhun kò gbajúmọ̀ ní ilè Afirika. A máa ń rí i ní Berber Chadic ni Afroasiatic, Nilotic Surmic ní ilẹ̀ Eastern Sudamic. Fún àpẹẹrẹ:

(i) Maasai, Eastern Nilotic Eastern Sudamic, àti Nilo-Saharan.

V S O

édól oltúףּání eףּkolìí

The person sees a gazelle.


Nínú àwọn èdè tí ń lo V S O àbọ̀ kìíní àti ìkejì máa ń tẹ̀lé Is á wá fùn wa ní VSOO Turkana bí àpẹẹrẹ:

V S O O

à-in-a-kin-i ayòףּ ףּide akimui


Nínú èdè SOV, adjuncts (afikun) maa ń síwájú Is, a wá fún wa ni SXOV tàbí SOXV bí ó se hàn ni –


(1) Aiki, Maban, Nilo-Saharan.

S O LOC V

Kàikàì ti tiףּíףּ gá tàk gán tàndàrkÈ

The child joined its mother at the pound

“X” yìí dùró fún ìkan lára àwọn àfìkún. Àfikún (adujunct) ni

Location post positional phrase “tak g∂n

Àwọn èdè SOV lè lo SOVX fun afikun (adjuncts) bí a se ríi ní Menade, pẹ̀lú atọ́kún Instrumental prepositional a bó a ti o túmọ̀ sí with a knife.

Mende, Western, Mande, Niger – Congo

S O V INST

è wúru tèe à bóa

      hé 		stick 	        cut 	 with  knife 

He cut the stick with a knife.

Gbólóhùn Àsẹ àti ìbèèrè (commands and questions) Ohun mẹ́ta ni a máa gbé yèwò. Èyí ibeere ni tàbí bẹ́ẹ̀ kọ (i) (Yes or no question) (2) Information word question (3) Indirect question.

Nínú èdè Africa Yes/no question most commonly involve only a question marker or morpheme at the end or the beginning of the sentences. Nínú èdè Africa ìbéèrè oní bẹẹni tàbí bẹ́ẹ̀kọ́ máa ń ni àmì ìbéèrè ní ìbẹ̀rẹ̀ tàbí ìparí

Linda is typical of many Niger-Congo and other langs, that use a question marker at the edge of the sentence. Linden i Ogidi nínú àwọn Niger Congo ti o n lo ìbéèrè alámì ni opìn gbólóhùn.

Linda, Banda, Adamawa –Ubangi, Niger-Congo

(a) `ce gú

he/she arrived she arrived

(b) cè gú à

he/she arrived Qm

Did she arrive?


Nínú èdè bíi silte wọ́n máa ń lo ohùn gbigbe sókè ní ìparí gbólóhùn, á lè lò ó gẹ́gẹ́ bíi yes/no question. Fun àpẹẹrẹ:

Silt’e, Ethio – Semitic, Afroasiatic

akkum tisiikbińaas way Qm

ó máa ń wáyé nínú èdè Haúsá náà.

Ohùn àwọn èdè wọ́nyí: Wande, Gur àti Kwa máa ń lọ sí ilẹ̀ ni. Nínú èdè àwọn konni, Gur ní ilè Ghana, vowel or nasal is lengthened and has a slow fall in pitch. Èyí túmọ̀ sí pé nínú èdè Konni fáwẹ̀lì tàbí aránmúpè wọn máa ń falẹ̀.

Àpẹẹrẹ nì díè saabú-u

Are you (pi) eating porridge?

Yes/no question tún máa ń wáyé nípa lilo negation (Ayisodi) “Didn’t he

go to Accra? Nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì tí a bá dáhùn bẹ́ẹ̀ni, ohun tí à ń sọ ni pé ò lọ sí Accra. Ìdàkejì rẹ̀ ni ó tọ̀nà ní ilẹ̀ Africa. Ṣùgbọ́n ní ilẹ̀: Ejagbam, Ekoid Bant

Benue – Congo àti Niger-Congo

(a) Ó – kà – jí ògàm à (Didn’t you go to the Qm market)

(b) nńǹ, (ń-kà-ji) Yes, (I didn’t go)

ÌYÓSÓDÌ Twó different kinds of negation should be distinguishes. Túmọ̀ sí pé orísìí àyísódì méjì ni a máa gbé yèwò. Àkọ́kọ́, A lè yí gbogbo gbólóhùn sí òdì. Ìkejì, ó sì lè jẹ́ àpólà kan nínú gbólóhùn bí àpólà orukọ ni a máa yí sódì.

VERBAL AFFIXES

Ọ̀nà tí ó gbajúmọ̀ tí wọ́n fi máa ń yi gbólóhùn sódì ni síse àtúnrọ àwọn ọ̀rọ̀ ìse. A yi kúrò ni ipò ìṣe lọ sí ìse aláyìísódì. Gbogbo ilẹ Benue-Congo ni wọn tí máa ń lò ó. Fún àpẹẹrẹ.

- Aghem, Grassfield, Banu, Benue-Congo, Niger-Congo

ò bò fí – ghGm He has hit the mat.

ò kà bó gbam-fò he has not hit the mat

Compound and complex sentences (Gbólóhùn ọlọ́pọ̀ awẹ́)

Compound sentewes-ni síse awẹ́ méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ pọ̀, ó máa ń jẹ́ odidi awẹ́ àti àfarahẹ.

Emphasis or focus’Àfojúsùn,

Àfojúsùn jẹ́ ohun pàtàkì tàbí information abẹ́nú nínú gbólóhùn. Ó jẹ́ ohun ti olùsọ gbà pé Oùgbọ́ kò gbọdọ̀ bá òun sọ. Èdè Africa máa ń lo ohùn nígbà mìíràn. Ṣùgbọ́n ohun ti wọ́n sabàá máa ń lò ni (i) yíyí padà kúrò ni ọ̀rọ̀ ìse tàbí kí wọ́n lo AUX àsèrànwọ́ ìṣe (2) use of special words (particles) (3) use of cleft-types constructions fún àpẹẹrẹ nínú èdè Ejaghan.

(a) à – nam bì-yù

buy yam

“She bought yams”

(b) à – nàm-é jén

Focus what

What did she buy

(c) à – nam-é bì-yù

She bought yams

Èdè A ghem ni àfojúsùn tó le (complex focus) In some cases it uses a focus particle ñ

(a) fù kí mò nyiףּ nõ á kí-bé

The rat ran in the compound.

(b) Fú kí mọ nyiףּ no á kí-bé

The rat ran (did not walk) in the compound

(c) Fù kí mọ nyiףּ á kí-bé no

The rat ran inside the conpound (not inside the house)

Àwọn èdè mìíràn lè lo àpepọ̀ verb changes and particles, gẹ́gẹ́ bí ó ti hàn nínú èdè Vute.

(a) mvèìn yi Gwáb-na tí ףּgé cene

The chief bought him a chicken

(b) Mvèìn yi Gwab-na-á ףּgé cene já

The Chief bought him a chicken.