John Harrison Burnett

(Àtúnjúwe láti Sir John Burnett)

John Burnett tí ó jẹ́ Principal àti Vice-Chancellor University of Edinburgh láàrin 1978 sí 1987 kú ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kéje, ọdún 2007.