Robert Menzies

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Australia
(Àtúnjúwe láti Sir Robert Gordon Menzies)

Robert Gordon Menzies je oloselu omo ile Australia ni Menzies. A bi i ni 1894. O je olootu ijoba ile Australia fun odun mokandinlogun. Ilu Jepart ni won ti bi i ni Victoria. O gba oye ninu ofin ni University Melborne. Ni aarin 1928 si 1934, o wa ni Victoria State Legislature. Nigba ti o se, o wo federal House of Representative. O di Attorney General ile Australia ni aarin 1935 si 1939. Leyin igba ti J. A. Lyons ku ni Menzies wa di olootu Australia. O fi ori oye sile funraare ni 1966.


Sir Robert Gordon Menzies

12th Prime Minister of Australia
Elections: 1940, 19461963
In office
26 April 1939 – 26 August 1941
AsíwájúEarle Page
Arọ́pòArthur Fadden
In office
19 December 1949 – 26 January 1966
AsíwájúBen Chifley
Arọ́pòHarold Holt
ConstituencyKooyong (Victoria)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1894-12-20)20 Oṣù Kejìlá 1894
Jeparit, Victoria
Aláìsí15 May 1978(1978-05-15) (ọmọ ọdún 83)
Melbourne, Victoria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnited Australia; Liberal
(Àwọn) olólùfẹ́Pattie Leckie