Sirat al-Nabi
Ìwé láti ọwọ́ Shibli Nomani
Siratun Nabi (Urdu: سیرت النبی) jẹ́ ìwé seerah alábala méje, tàbí ìwé ìtàn ìgbésí-ayé òjíṣẹ́ ẹ̀sìn Islam, Muhammad, èyí tí Shibli Nomani àti Sulaiman Nadvi kọ. Èyí jẹ́ iṣẹ́ Shibli Nomani tí ọjọ́ rẹ̀ kò ì pẹ́ púpọ̀, tí ó sì gbajúmọ̀ jù lọ.[1][2][3][4]
Cover of Urdu Version | |
Olùkọ̀wé | Shibli Nomani |
---|---|
Àkọlé àkọ́kọ́ | سیرت النبی |
Translator | Muhiuddin Khan |
Country | British India |
Language | Urdu |
Subject | Muhammad |
Genre | Biography |
Publisher | Darul Musannefin Shibli Academy |
Publication date | 1918–1955 |
Media type | Hardcover |
OCLC | 10695489 |
297.09 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àdàkọ:Cite thesis
- ↑ Àdàkọ:Cite thesis
- ↑ Shah, Mutahir; Irshad, Dr Saira; Bibi, Brakhna (2021-12-31). "سیرت النبیﷺ میں شبلی نعمانی کا اسلوبِ تحقیق: Shibli Nomani's research style in Sirat-un-Nabi (PBUH)" (in en-US). Al-Duhaa 2 (02): 274–281. doi:10.51665/al-duhaa.002.02.0131. ISSN 2710-0812. https://www.alduhaa.com/index.php/al-duhaa/article/view/131.
- ↑ Àdàkọ:Cite thesis