Siyar A‘lām al-Nubalā’ (Lárúbáwá: سير أعلام النبلاء‎) jẹ́ ìwé atúmọ̀ èdè ajẹmọ́ ìgbésí-ayé ẹ̀dá, èyí tí al-Dhahabi kọ tó ní ṣe pẹ̀lú ìtàn ìgbésí-ayé àwọn Mùsùlùmí lásìkò al-Dhahabi.[1] Ìpín méjì àkọ́kọ́ ti ìwé Siyar oní ìpín mẹ́rìnlá yìí dá lórí ayé Muhammad àti Rashidun, èyí tí wọ́n yọ lára Tarikh ti al-Dhahabi.[2] Al-Dhahabi pín ìwé náà sí abala ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìran tí oníkálùkú wọn gbé.[3].

Siyar A'lam al-Nubala'
Olùkọ̀wéAl-Dhahabi
Àkọlé àkọ́kọ́سير أعلام النبلاء
CountryMamluk Sultanate
LanguageArabic
SubjectBiographical dictionary
GenreBiography
Published14th century
Media typeManuscript
Pages28 volumes

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "نبذة عن كتاب سير أعلام النبلاء". موضوع (in Èdè Árábìkì). Retrieved 2023-04-04. 
  2. Marouf, Bashar Awwad (1996). "Editor's Introduction". In Arna’ūt, Shu‘ayb (in ar). Siyar A‘lām al-Nubalā’ (11th ed.). Beirut: Resalah Publishers. pp. 93–94. 
  3. "الذهبي ومنهجه في سير أعلام النبلاء - بشار عواد معروف". ar.islamway.net (in Èdè Árábìkì). Retrieved 2023-04-04.