Slindile Nodangala
Slindile Nodangala (bíi ni ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹfà ọdún 1972) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Ruby Dikobe tí ó kó nínú eré Generations. Nodangala dàgbà sí ìlú Durban, ìyá bàbà rẹ̀ ló sì tọju rẹ̀. Nodangala tí bí ọmọ méjì.[1]
Slindile Nodangala | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Slindile Nodangala 23 Oṣù Kẹfà 1972 Durban, South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1989–present |
Àwọn ọmọ | 2 |
Iṣẹ́
àtúnṣeNodangala ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Lyceum Theater ni ìlú London ni ọdún 2001. Ó kópa nínú eré Generations láti oṣù kẹfà ọdún 2011 di oṣù kejìlá ọdún 2014.[2] Ó ti farahàn nínú eré Izulu lami ni ọdún 2008 àti The Lion King.[3][4]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Slindile Nodangala - Actress". Woman Online Magazine. 28 May 2013.
- ↑ "Slindile Nodangala". Tvsa.co.za. Retrieved 2015-06-26.
- ↑ "Slindile Nodangala". IMDb.com. Retrieved 2015-06-26.
- ↑ "Slindile Nodangala". LinkedIn. Retrieved 2015-06-26.