Snail pepper soup
Ìwé-alàyé[ìdá]
Snail pepper soup jẹ́ oúnjẹ ìbílè Ìhà Gúsù-Ìlà Òòrùn ti Nàìjíríà. Ìgbín Áfíríkà tó pọ̀ ni ọ̀kan pàtàkì lára èròjà tí a fi ń sè é. Ọ̀bẹ̀ ìgbín náà wọ́pọ̀ ni àgbègbè e Niger Delta àti àwọn ènìyàn láti Ìpínlẹ̀ Cross River .[1]
Àwọn ohun tí a fi ń pèsè rẹ̀
àtúnṣeÀwọn ohun tí a máa fi yọ Igbin náà kúrò nínú Ìkarahun ni wọ̀nyí Ọ̀sàn wẹ́wẹ́, iyọ̀, Gàrí tàbí Álọ̀mù. Àwọn èròjà yòókù ni ata, uziza powder, scent leaf, ehuru àti ewé Utazi.[2] Ọbẹ̀ ìgbín náà ma ń wọ́n nígbà ẹ̀rùn nítorí pé ìgbín má ń sáfẹ́rẹ́ nígbà náà àmọ́ ọ̀bẹ̀ ìgbín má ń wọ́pọ̀ ni ìgbà òjò.
Àwọn oúnjẹ mìíràn
àtúnṣeWọ́n tún máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú àgbàdo gígún àti ìrẹsì.[3]
Tún wo
àtúnṣe- Frejon
- Palm nut soup
Àwọn ìtọ́kasi
àtúnṣe- ↑ "Have You Tried The Classic Snail Pepper Soup?". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-01-28. Archived from the original on 2022-07-01. Retrieved 2022-07-01.
- ↑ Online, Tribune (2016-12-10). "How to make mouth watering Nsala soup". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-01.
- ↑ Garcia, Susana (2019-11-14). "Snail Soup". Medium (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-01.