Ìròjinlẹ̀ aláwùjọ

(Àtúnjúwe láti Social theory)

Awon ìròjinlẹ̀ aláwùjọ tabi irojinle awujo je awon ilana isese onirojinle ti wo unje lilo lati se agbeka ati se itumo awon isele awujo larin inu ile-eko ironu pati kan. Bi irinse to se koko fun awon asesayensi alawujo, awon irojinle je mo ijiyan lati atijo lori awon oro-onaise to fesemule ati tosegbarale julo (f.a. iseonididaloju ati iseilodionididaloju), ati bakanna bi ipa ti opo tabi araunse unko. Awon irojinle awujo pato kan ungbiraka lati je ti onisayensi, aseaijuwe ati alaifisegbekan ni gbamigbamu. Awon irojinle ajodu, lodi si eyi, ni ipo to duro lori ise pato kan, be sini oun se ayewo awon iru oloro-erookan to wa ninu ironu alasabile to gbale.

Ibere irojinle awujo soro lati se wari, sugbon awon ijiyan lori re unsaba pada si Griisi Ayeijoun Àdàkọ:Harv. Lati inu awon ipilese yi ninu imoye Apaiwoorun ni irojinle adehun awujo Olaju, iseonididaloju oloro-awujo, ati sayensi awujo odeoni ti dide. Loni, 'sayensi awujo' je lilo lati toka si oro-awujo, oro-okowo, sayensi oloselu, oro-ofin, ati awon beebe lo. Irojinle awujo bi be je nipa awon eka eko pupo; oun mu erookan wa lati inu papa orisirisi bi oro-edaomomiyan ati awon ikeko amohunmaworan. Irojinle awujo ti ko ni ilana, tabi ti olukowe ko wa lati inu sayensi awujo tabi oloselu oniomowe, se toka si bi "isealagbewo awujo" tabi "aroye awujo". Bakanna, "isealagbewo asa" le toka si iweakeko onilana asa ati onimookomooka, ati si iru awon ikowe ti ki se ti olomowe tabi ti won je ti oniroyin.

E tun wo

àtúnṣe

Ijapo ode

àtúnṣe

Àdàkọ:Wikibooks

References

àtúnṣe
  • Baert, Patrick; Silva, Filipe Carreira da (2010). Social Theory in the Twentieth Century and Beyond. Cambridge, UK: Polity Press. ISBN 978-0745639819. 
  • Bell, David (2008). Constructing Social Theory. Lanham, MD: Rowman & Littlefield. ISBN 978-0742564282. 
  • Berberoglu, Berch (2005). An Introduction to Classical and Contemporary Social Theory: A Critical Perspective, Third Edition. Lanham, MD: Rowman & Littlefield. ISBN 978-0742524934. 
  • Berger, Peter; Luckmann, Thomas (1966). The Social Construction of Reality: A Treatise in the Sociology of Knowledge. Garden City NY: Anchor Books. ISBN 0-385-05898-5. 
  • Harrington, Austin (2005). Modern Social Theory: An Introduction. Oxford, UK: Oxford University Press. ISBN 978-0199255702.