Sofia Assefa ni a bini ọjọ kẹrinla, óṣu November, ọdun 1987 si Ilu Tenta, South Wollo jẹ elere sisa ti ọna jinjin to dalori steeplechase ti metres ẹgbẹrun mẹta. Sofia gba ami idẹ ọla ti silver ni summer olympics ti ọdun 2012[1][2].

Sofia Assefa
Assefa at the 2010 Memorial van Damme
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kọkànlá 1987 (1987-11-14) (ọmọ ọdún 37)
Addis Ababa, Ethiopia
Height1.67 m (5 ft 5+12 in)
Weight52
Sport
Orílẹ̀-èdè Ethiopia
Erẹ́ìdárayáTrack and field
Event(s)3000 metres steeplechase

Àṣèyọ̀ri

àtúnṣe

Sofia kopa ninu idije ilẹ afirica nibi to ti pari pẹlu ipo kẹrin ni ọdun 2008. Ni ọdun 2019, Sofia pari pẹlu ipo kẹtala ninu idije agbaye[3]. Ni ọdun 2012, Sofia gba ami ẹyẹ ọla ti silver ninu summer olympic ti steeplechase ti ẹgbẹrun mẹta Metre[4]. Ni ọdun 2013, Sofia gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ninu idije agbaye to aaye ni Moscow[5][6]. Ni ọdun 2015, Sofia gba ami ẹyẹ ti ọla ti gold ni ere ilẹ afirica to waye ni Brazzaville.

Itọkasi

àtúnṣe
  1. Sofia
  2. Sofia Assefa Profile
  3. World Championships
  4. ATHLETICS,3000M STEEPLECHASE WOMEN FINAL
  5. IAAF World Championships in Moscow
  6. 2013 World Championships