Sohail Ahmed (Pùnjábì: سہیل احمد) (tí wọ́n bí ní 1 May 1963), tó tún ń jẹ́ Azizi (Urdu: عزیزی), jẹ́ òṣèrékùnrin, apanilẹ́rìn-ín àti olùdarí fíìmù ti ilẹ̀ Pakístàn.[1]

Sohail Ahmed
Ahmed in 2011
PseudonymAzizi
Ìbí1 Oṣù Kàrún 1963 (1963-05-01) (ọmọ ọdún 61)
Gujranwala, Punjab, Pakistan
Medium
  • Actor
  • Comedian
  • Director
Genres
Subject(s)
Pride of Performance Award Recipient
Sohail Ahmed was recipient of the Pride of Performance Award 2011
Látọwọ́ Asif Ali Zardari (President of Pakistan)
Orílẹ̀-èdè Islamic Republic of Pakistan
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ {{{website}}}

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Pamment, Claire (24 May 2017). Comic Performance in Pakistan: The Bhānd (illustrated ed.). Springer, 2017. pp. 207. ISBN 978-1137566317. https://books.google.com/books?id=ACclDwAAQBAJ&q=sohail+ahmed+born&pg=PA207. Retrieved 24 September 2022.