Sonya Spence
Sonya Spence jẹ́ akọrin, olórin ìfẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Jamaica. Lára àwọn orin tí ó kọ tí ó lókìkí ni Jet Plane[1], In the dark[2] àti Let Love Flow On.[3]
Sonya Spence | |
---|---|
Ìbẹ̀rẹ̀ | Jamaica |
Irú orin | Rágà àti orin ìfẹ́ |
Occupation(s) | Akọrin, Olórin ìfẹ́ |
Years active | 1970s |
Associated acts | Sonia Pottinger |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "IBB, what a drag!". The Nation Newspaper. Retrieved June 7, 2017.
- ↑ David Vlado Moskowitz (2006). Caribbean Popular Music: An Encyclopedia of Reggae, Mento, Ska, Rock Steady, and Dancehall. Greenwood Publishing Group. pp. 271–. ISBN 978-0-313-33158-9. https://books.google.com/books?id=dDKfGRCq73cC&pg=PA271.
- ↑ "Various - Jeremy Underground Presents Beauty". Residentadvisor.net. Retrieved June 7, 2017.