Sophie Ndaba
Sophie Lichaba (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1973)[1], jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.
Sophie Lichaba | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Sophie Mphasane 8 Oṣù Kẹta 1973 Soweto, South Africa |
Orúkọ míràn | Sophie Ndaba |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1992 – present |
Olólùfẹ́ |
|
Alábàálòpọ̀ | Keith Harrington (2011–2013) |
Àwọn ọmọ |
|
Ẹ̀kọ́
àtúnṣeÓ lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ni Zimbabwe[2], ìyá rẹ gbé lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn aláìní ìyá kí ó ba le ni ẹ̀kọ́ gidi.[3] Bàbá rẹ̀ kú ní ọdún 2016.[4] [5]Ó bí ọmọ méjì fún ọkọ rẹ tẹ́lẹ̀, Themba Ndaba[6]. Ní ọdún 2018, àwọn kan gbé aruyewuye jáde pé Lichaba tí kú.[7]
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
àtúnṣe- Class of '92
- Egoli: Place of Gold
- Generations[8]
- Gog' Helen
- Yizo Yizo
- Soul City
- She is King
- Isidingo
- High Rollers - Season 2
- Lockdown
Àwọn amì-ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá rẹ̀
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Sophie Ndaba Biography: Weight loss, Illness, Age, Husband, Children". ZAlebs. Africa New Media Group. 13 September 2013. Archived from the original on 2019-10-26. Retrieved 2020-03-23.
- ↑ Memoir. [1] Archived 2019-10-26 at the Wayback Machine., Sophie Ndaba Biography. Retrieved on 26 October 2019
- ↑ Chidavaenzi, Phillip (September 2015). "Fashion keeps me young – Sophie Ndaba". Newsday. Retrieved 2020-03-23.
- ↑ "Sophie Ndaba still believes in love". Entertainment SA. 2017. Retrieved 2020-03-23.
- ↑ "Sophie Ndaba reflects on losing her dad six weeks ago". SowetanLIVE. Arena Holdings. 4 November 2016. Retrieved 2020-03-23.
- ↑ Winters, Hope (2017-12-11). "Sophie Ndaba secretly weds third husband in Italy". All4Women. https://www.all4women.co.za/1325083/entertainment/sa-celebs/sophie-ndaba-secretly-ties-knot.
- ↑ https://www.iol.co.za/entertainment/celebrity-news/local/sophie-lichaba-opens-up-about-going-to-the-emergency-room-during-covid-19-48809245
- ↑ The South African TV authority. [2], Sophie Ndaba, 2014. Retrieved on 3 October 2014.
- ↑ 9.0 9.1 "Sophie Ndaba Biography: Weight loss, Illness, Age, Husband, Children". ZAlebs. Africa New Media Group. 13 September 2013. Archived from the original on 2019-10-26. Retrieved 2020-03-23.
- ↑ "Sophie Ndaba", Women of inspiration, Cape Town, 2010. Retrieved on 3 October 2014.