Stefanos Pavlakis (tí wọ́n bí ní ọdún 1974) jẹ́ olùdarí eré, ònkọ̀tàn àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Gíríìsì.[1][2] Ó ti lọ́wọ́sí tó sì ti nípa lọ́pọ̀lọpọ̀ nínu àwọn sinimá orílẹ̀-èdè Bẹ̀nìn pẹ̀lú ṣíṣe àwọn fíìmù ìtàn-àkọọ́lẹ̀ bíi The Eye of the Beholder, Studio Harmattan àti Drive Through.[3]

Stefanos Pavlakis
Ọjọ́ìbíStefanos Pavlakis
1974
Athens, Greece
Orílẹ̀-èdèGreek
Ẹ̀kọ́Edinburgh Napier University
University of Dundee
Duncan of Jordanstone College of Art and Design
Iṣẹ́Director, writer, producer
Ìgbà iṣẹ́2005–present
Websitehttps://www.stefanos-pavlakis.com

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Practice Statement, Profile & C.V.". Stefanos Pavlakis official website. Retrieved 27 October 2020. 
  2. "Stefanos Pavlakis: Film Director (documentary)". behance. Retrieved 27 October 2020. 
  3. "Introducing Stefanos Pavlakis". Beyond Storytelling. Retrieved 27 October 2020.