Stella Mbachu jẹ ọkan lara awọn agbàbọọlu lobinrin Naigiria ti a bini 16, óṣu April ni ọdun 1978 ni Mgidi. Èlère àgbàbọọlu naa ti ṣere fun Super Falcons ati River Angels[1][2].

Stella Mbachu
Personal information
OrúkọStella Mbachu
Ọjọ́ ìbí16 Oṣù Kẹrin 1978 (1978-04-16) (ọmọ ọdún 46)
Ibi ọjọ́ibíMgbidi, Nigeria
Ìga1.65m
Playing positionForward
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Rivers Angels F.C.
National team
1999–2014Nigeria women's national football team88(20)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Aṣeyọri

àtúnṣe
  • Stella ṣe àyọri ninu idije awọn obinrin ilẹ Afirica ni ọdun 1998 to waye ni Abeokuta. Elere naa ti ṣe àsóju fun Super Falcon ninu Cup FIFA awọn obinrin àgbaye to waye ni ókè ókun ni ọdun 1999. Obinrin naa ti kopa ninu idije awọn obinrin ilẹ Afirica to waye ni ilẹ South Afirica ni ọdun 2010. Mbachu jẹ ọkan lara ẹgbẹ ninu ere idije Namibia awọn obinrin ilẹ Afirica nibi ti ó ti jẹ àṣoju fun Super Falcons ni ọdun 2014 lẹyin naa ti elere naa si fiẹyinti[3][4].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.worldfootball.net/player_summary/stella-mbachu/
  2. https://www.eurosport.com/football/stella-mbachu_prs281743/person.shtml
  3. https://www.goal.com/en-ng/news/4093/nigerian-football/2014/10/29/5594081/stella-mbachu-announces-retirement-from-football
  4. https://www.vanguardngr.com/2014/10/stella-mbachu/amp/