Stellah Nantumbwe
Stella Nantumbwe jẹ́ òṣèré àti omidan Uganda ní ọdún 2013.[1] Òun ni aṣojú Uganda ní Big Brother Africa ní ọdún 2014.[2][3]
Stellah Nantumbwe | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Stella Nantumbwe 1991 (ọmọ ọdún 32–33) |
Orílẹ̀-èdè | Ugandan |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Greenwich (Bachelor of Science in Business Computing) |
Iṣẹ́ | Beauty Pageant Contestant, Pageant Coach & Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2013–present |
Gbajúmọ̀ fún | Miss Uganda & Big Brother Africa |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Stella sí ìdílé Angela Nakiyonga àti Rogers Nsereko ní ọdún 1991 ní orílẹ̀ èdè Uganda. Òun ni àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ méjìlá tí àwọn òbí rẹ bí. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Buganda Road Primary School àti Kabojja International Secondary School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Greenwich níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Business Computing ní ọdún 2012.[4][5]
Iṣẹ́
àtúnṣeNí ọdún 2013, nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìlélógún, ó lọ fún ìdíje omidan Uganda, ó sì gbé igbá orókè nínú ìdíje náà.[6] Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 2014, ó gboyè omidan tó gbajúmọ̀ jù lórílẹ̀-èdè Uganda.[7][8] Ní oṣù kẹsàn-án, ọdún 2013, ó ṣe aṣojú fún Uganda níbi ìdíje omidan àgbáyé.[9][10] Ó kópa níbi ìdíje Big Brother Africa ní ọdún 2014 gẹ́gẹ́ bí aṣojú fún Uganda.[11][12] Ellah ti kópa nínú eré fíìmù, ó sì ti ṣe atọ́kun ètò lórí tẹlẹfíṣọ̀nù. Ó ko ipa Isabella Arroyo nínú eré El Cuerpo del Deseo ní ọdún 2016.[13] Ní ọdún 2017, ó kópa nínú eré Bella[14][15][16]. Ní ọdún 2018, ó ṣe atọ́kun ètò Scoop on Scoop lóri Urban TV. Ó jẹ́ ìkan lára àwọn adájọ́ fún ìdíje omidan Uganda ní ọdún 2018.[17] Òun ni igbá kejì Ààrẹ fún Africa Music Industry Awards.[18]
Àwọn Ìtọ́kàsi
àtúnṣe- ↑ Batte, Edgar (15 July 2013). "Stellah Nantumbwe is Miss Uganda". Daily Monitor. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Odeke, Steven (9 December 2014). "Time to look for a job - Ellah". New Vision. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Irene Namarah (2 November 2016). "Sophisticated and bitchy Stella Nantumbwe". Matooke Republic. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Kalema, Lawrence (12 March 2018). "Former Miss Uganda, Stella Nantumbwe Dumps Boyfriend". Kampala: UgandanBuzz.Com. Retrieved 14 August 2018.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Ghafla.com (20 February 2018). "Star Struck Tuesday: Stella Nantubwe To Feature In Nigerian Film". Kampala: Ghafla.com. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Odeke, Steven (26 May 2013). "Nantumbwe Wins Miss Uganda 2013 Central Region". New Vision. Kampala. Retrieved 11 August 2018.
- ↑ Baligema, Isaac (14 July 2013). "Stella Nantumbwe crowned Miss Uganda 2013". New Vision. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Eupal, Felix (14 July 2013). "Stella Nantumbwe is Miss Uganda 2013". The Observer (Uganda). Kampala. Archived from the original on 11 December 2018. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Edgar R. Batte (11 September 2013). "Miss Uganda Optimistic About Taking World Crown". Daily Monitor. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ BellaNaija.com (2 October 2013). "Glamorous Belles! See What Our African Queens Wore at the Miss World 2013 Finale in Bali, Indonesia". Lagos: BellaNaija.com. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Businge Brian Franco (December 2014). "Stella Nantumbwe Finally Evicted From The House – BBA Hotshots". Kampala: Howwe.Biz. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Carol Natukunda, and Halima Nampiima (22 December 2014). "Ellah: I had plans to marry BBA's Idris". New Vision. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Namarah, Irene (31 October 2016). "Will Ellah nail Isabel’s character in Uganda’s Second Chance?". Kampala: Matooke Republic. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Big Eye (2 July 2018). "Stella Nantumbwe Lands Nollywood Movie Role". Kampala: Big Eye Uganda. https://bigeye.ug/stella-nantumbwe-lands-nollywood-movie-role/.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Isaac (5 August 2015). "Stella Nantumbwe 'Ellah' Gets A New Programme On Urban TV". Kampala: Chano8.Com. Archived from the original on 23 February 2020. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Ssempijja, Reagan (23 October 2017). "Matt Bish Films premieres star-packed movie Bella". New Vision. Kampala: New Vision Publications. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Ahumuza, Allan (24 July 2018). "Former Miss Uganda Contestant Attacks Pageant Judges". Kampala: Chano8.Com. Archived from the original on 16 January 2020. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Josh Ruby (February 2018). "Stella Nantumbwe Ellah To Host African Music Industry Awards". Kampala: Mbu Uganda. https://mbu.ug/2018/02/28/stella-nantumbwe-ellah-host-african-music-industry-awards/.