Stephanie Coker
Stephanie Omowunmi Eniafe Coker (bíi ọjọ́ Kejìdínlógbon oṣù kọkànlá ọdún 1988)[1][2][3] jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti olùdarí ètò lórí telifisoonu fún MTV Base Africa àti Ebony Life TV.[4][2] Ó kópa nínú eré gbajúmò Tinsel [5]
Stephanie Coker | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Stephanie Omowunmi Eniafe Coker 28 Oṣù Kọkànlá 1988 Lagos, Lagos State, Nigeria |
Ibùgbé | Lagos, Lagos State, Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | Brunel University London |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún | TV Presenter at MTV Base Africa |
Olólùfẹ́ | Olumide David Aderinokun |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọn bí Stephanie sì ipinle Eko ni orile ede Nàìjíríà ṣùgbọ́n ó lọ sí North London ni United Kingdom láti ìgbà tí ó ti wà ní ọmọ ọdún kan.[6][2] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ St Mary's Church of England Primary school ni North London. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Brunel University níbi tí ó tí ká ẹ̀kọ́ imọ Media and Communications.[1][6][7][8] Ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Brunel náà ni ó ti kọ́kọ́ ṣíṣe fún MTV, Channels Four àti Media Moguls PR.[9]
Ìṣe
àtúnṣeLondon
àtúnṣeNí ọdún 2010, ó gbé igbá o ròkè ninu ìdíje MTV freederm presenter competition èyí ló fún ní àǹfààní láti kópa nínú ìpolówó kàn lórí telefisi telifisoonu.[10] Ní ọdún 2011, ilé iṣẹ́ ''London 360'' gbá láti ṣe atọkun fún wọn.
Nigeria
àtúnṣeStephanie padà sí ìlú Nàìjíríà ni odun 2011 ó sì bẹẹrẹ sì ni ṣíṣe fún MTV Base Africa gẹ́gẹ́ bíi atọkun fún ètò Street Request. Ó tí ṣíṣe pẹlu Cool Fm lórí ètò Oasis Show àti Africa Magic lórí ètò Tinsel.[11] Ní ọdún 2013, òun pẹlu Bovi àti pearl ni atọkun fún ètò Guinness colorful world of more concert.[12][13] Ó farahàn nínú ojú ìwé àkọ́kọ́ tí Exquisite magazine ni odun 2015.[14][15][16]. Òun ní atọkun ètò Ohùn Nàìjíríà ni ọdún 2016.[17] Ní ọjọ́ kẹfa oṣù Kejìlá ọdún 2013, ilè iṣẹ́ Bailey Nigeria fi Stephanie Coker àti Veronica Ebie-Odeka ṣe atọkun fún ètò Baileys Boutique.[18][19][20]
Ebun
àtúnṣeO gbà ẹ̀bùn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tó tayọ julọ ni ọdún 2014 láti ọwọ́ Exquisite Lady of the Year (ELOY).[21][22]
Ìgbéyàwó
àtúnṣeO se ìgbéyàwó pẹ̀lú Olumide Aderinokun ni ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 2017.[23][24]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "MTV VJ, STEPHANIE COKER IN A CHAT WITH WANNA". July 17, 2013. Archived from the original on June 2, 2020. https://web.archive.org/web/20200602062739/https://rhodiesworld.com/mtv-vj-stephanie-coker-in-a-chat-with-wanna-i-enjoy-working-with-denrele-edun/.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 "I can’t kill myself over a man". March 30, 2014. Archived from the original on October 20, 2015. https://web.archive.org/web/20151020091737/http://www.punchng.com/spice/essence/i-cant-kill-myself-over-a-man-stephanie-coker/.
- ↑ "It’s Stephanie Coker’s Birthday Today!". November 28, 2014. Archived from the original on April 9, 2019. https://web.archive.org/web/20190409143730/http://onobello.com/stephanie-cokers-birthday-today-check-super-glam-plans-day/#sthash.j3duOBXV.dpbs.
- ↑ "360Chat With MTV Base’s Stephanie Coker". July 26, 2013. Archived from the original on April 9, 2019. https://web.archive.org/web/20190409172209/https://www.360nobs.com/2013/07/360chat-with-mtv-bases-stephanie-coker/.
- ↑ "Tinsel Cast". Tinsel Today. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ 6.0 6.1 "10 Questions For TV Host & Actress Stephanie Coker". TWMagazine. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "Next To Blow: I Strive To Be The Ultimate Presenter – Stephanie Coker". Aloteda's Blogzine”. Archived from the original on 6 July 2020. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "MTV Base VJ signs management deal". Pulse NG. March 5, 2015. http://pulse.ng/celebrities/stephanie-coker-mtv-base-vj-signs-management-deal-id3543224.html. Retrieved 5 May 2015.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "London 360 (Community Channel) :Meet the Team". CommunityChannel.Org. Archived from the original on 4 March 2016. Retrieved 5 May 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "15 females to watch out for in 2015". The Pulse NG. Archived from the original on 12 March 2017. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "Honestly, Stephanie Coker is an Amazing Presenter and Interviewer". Zen Magazine Africa. Archived from the original on 7 July 2017. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "How Bow Wow missed his flight after being paid to host #Colourfulworldofmore concert". Daily Star. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "Photos from the Guinness colourful World of more Star Studded Concert in Lagos". Enquizzle. November 5, 2013. http://enquizzle.blogspot.com/2013/11/photos-from-guinness-colourful-world-of.html. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "TV Beauty! Stephanie Coker Covers New Edition of Exquisite Magazine jaguda.com/2015/02/13/tv-beauty-stephanie-coker-covers-new-edition-exquisite-magazine/ © Jaguda.com". Jaguda. Archived from the original on 24 July 2016. https://web.archive.org/web/20160724083022/http://jaguda.com/2015/02/13/tv-beauty-stephanie-coker-covers-new-edition-exquisite-magazine/. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "TV host is picture perfect on the cover of Exquisite Magazine". Pulse Nigeria. Archived from the original on 23 April 2017. https://web.archive.org/web/20170423161130/http://pulse.ng/fashion/stephanie-coker-tv-host-is-picture-perfect-on-the-cover-of-exquisite-magazine-id3482233.html. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "Subtle Chic! Stephanie Coker Covers the 77th Issue of Exquisite Magazine". Bella Naija. February 2015. http://www.bellanaija.com/2015/02/13/subtle-chic-stephanie-coker-covers-the-77th-issue-of-exquisite-magazine/. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "IK Osakioduwa, Stephanie Coker to host The Voice Nigeria - Vanguard News". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2016-04-21.
- ↑ "Baileys Nigeria Official Facebook Page". BaileysNigeria.
- ↑ "Photos: Veronica Odeka & Stephanie Coker Debut New Radio Show… Baileys Boutique". Ladun Liadi. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "Meet the Hosts of Baileys Boutique: Stephanie and Veronica". Linda Ikeji. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "BN Red Carpet Glam: The 2014 Exquisite Lady of the Year (ELOY) Awards". Bella Naija. http://www.bellanaija.com/2014/12/01/red-carpet-glam-funke-akindele-stephanie-coker-osas-ighodaro-more-attend-the-2014-eloy-awards/. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "All the winners from the 2014 ELOY awards". Pulse NG. Archived from the original on 20 December 2016. Retrieved 5 May 2015.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2018-09-28. Retrieved 2020-05-11.
- ↑ "Stephanie Coker & Olumide Aderinokun's White Wedding is this Saturday! - BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-09-08.