Steve Eboh
Steve Eboh /θj/, tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Ajebo, jẹ́ òṣẹ̀rékùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún àwọn ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù Extreme Measure, Extreme Measure 2 àti Lionheart. Yàtọ̀ sí ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù àgbéléwò, Eboh jẹ́ olùṣàgbéjáde fíìmù, olóòtú ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán àti onínúure ènìyàn.[2]
Steve Eboh | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Steve Eboh Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Ajebo |
Ẹ̀kọ́ | Mass Communication, University of Lagos |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | Actor, producer, television personality, philanthropist |
Ìgbà iṣẹ́ | 1996–present |
Ìgbésí ayé ara ẹni
àtúnṣeÓ jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Achi ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Oji River ní ìpínlẹ̀ Enugu. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè B.A nínú ẹ̀kọ́ Mass communication láti University of Lagos.[3]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeNí ọdún 1996, ó ṣe ìfarahàn àkọ́kọ́ nínú fíìmù Karishika àti apá kejì rẹ̀, ìyẹn Karishika 2. Lẹ́yìn ìgbà náà, ó tẹ̀síwájú láti kópa nínú àwọn fíìmù àgbéléwò mìíràn. Ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bí i Taboo, Ikuku, Narrow Escape, Evil Passion, àti The Concubines.[4] Ní ọdún 2018, ó farahàn nínú fíìmù Lionheart.[5][6]
Ní oṣù kẹfà, ilé-iṣẹ́ 'GOVOIL' tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ epo rọ̀bì ṣe ìkéde láti fi Eboh hàn gẹ́gẹ́ bí i aṣojú wọn.[7] Bákan náà, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i Igbá-kejì Ààrẹ fún Actors Guild of Nigeria (AGN), àti Alága National Caretaker Committee, AGN.[8] Ò jẹ́ olùdarí Confirm Projects International Ltd. fún ìgbà díẹ̀.[9]
Àtòjọ àwọn fíìmù tó kópa nínú
àtúnṣeỌdún | Fíìmù | Ipa | Irúfẹ́ fíìmù | Ìtọ́ka. |
---|---|---|---|---|
1998 | Karashika | Car Driver | Horror | |
1999 | Issakaba | Elder | Action / Drama / Horror | |
2003 | Oga and His Boys | Usman | Drama | |
2005 | Days of Bondage | Lover Boy | Drama | |
2008 | Kiss My Pain | Chief Obika | Home movie | |
2008 | Kiss My Pain 2 | Chief Obika | Home movie | |
2009 | Honest Deceiver | Senator | Home movie | |
2009 | Honest Deceiver 2 | Senator | Home movie | |
2011 | Thanks for Coming | Benson | Home movie | |
2011 | Thanks for Coming 2 | Benson | Home movie | |
2011 | Royal King | Home movie | ||
2011 | Royal King 2 | Home movie | ||
2011 | Gallant Babes | Benson | Home movie | |
2011 | Gallant Babes 2 | Benson | Home movie | |
2018 | Lionheart | Ministry of Transport Director #1 | Home movie |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Actors Are More Concerned About Makeup Than Their Roles - Steve Eboh". happenings. Archived from the original on 9 November 2020. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ "Steve Eboh (Ajeboh) Biography and Net Worth - Austine Media". pinterest. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ "Domestic oil firm picks Nollywood’s Steve Eboh as brand ambassador". sunnewsonline. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedsunnewsonline2
- ↑ "Lionheart (2018)". dream13. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ "Genevieve’s `Lionheart’ Set To Premiere In Toronto Film Festival". thewhistler. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedsunnewsonline3
- ↑ "Call for Removal of Service Chiefs Unjust – Steve Eboh". This Day. Retrieved 8 November 2020.
- ↑ "Nollywood: Committee pledges credible election for Actors Guild". today. Retrieved 8 November 2020.