Stumai Abdalla
Personal information
Playing positionIwájú
National team
Tanzania
† Appearances (Goals).

Stumai Abdalla jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún ẹgbẹ <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin Tanzania . Ní ọdún 2019, ó jẹ́ asáájú fún ikọ̀ ẹgbẹ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède nígbà tí wọ́n ń jà fún ife ẹ̀yẹ ìdíje CECAFA Women's Championship

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe