Sùltánù ìlú Sókótó

(Àtúnjúwe láti Sultan of Sokoto)

Sùltánù ìlú Sókótó tabi Sultani ilu Sokoto ni oruko oye Kalifu ilu Sokoto, ohun na lo si tun je baba agba fun awon musulumi ni Apaariwa Naijiria.

Sokoto caliphate.png

Sultani ori oye lowolow ni Muhammed Sa'adu Abubakar.


ItokasiÀtúnṣe