Supo Shasore
Ọláṣùpọ̀ Sháṣore, Agbejoro Agba ni Orile-ede Naijiria (ọjọ́ ìbí - ọjọ́ kejì-lé-lógún Oṣù Kíní ọdún 1964) jẹ́ onimo nipa ofin. Ó jẹ okan lara awon oludasile ati alabaṣepọ ninu ile-iṣẹ ofin ti ALP (Ofin Ilu Afirika). O jẹ agbejoro agba ati alabojuto eka idajo ti ipinle Eko lati ọdun 2007 titi odun 2011. Shasore jẹ́ Agbẹjọ́rò Àgba~a ti Nigeria (SAN) ati okan gboogi ninu egbe awon Alagbawi ni orile ede Naijiria. Oun ni alaga ana fun awon Egbe Alagbawi ati Onilaja ti eka ofin Okoowo ni Eka awon Amofin ni orile ede Naijiria.