Susan Rice
Olóṣèlú
Susan Elizabeth Rice (ojoibi November 17, 1964) je diplomati ara Amerika, elegbe think-tank tele, ati lowolowo Asoju Orile-ede Amerika ni Agbajo Asokan awon Orile-ede. Rice ti sise tele ni Igbimo Abo Onitomoorile-ede ati Oluranwo Alakoso Oro Okere fun Afrika ni asiko igba keji Aare Bill Clinton. Rice je pipe ni Asoju si Asokan awon Orile-ede pelu ifenuko alainitako ni Ile Alagba Amerika ni January 22, 2009.
Susan Rice | |
---|---|
27th United States Ambassador to the United Nations | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga January 22, 2009 | |
Ààrẹ | Barack Obama |
Asíwájú | Zalmay Khalilzad |
12th Assistant Secretary of State for African Affairs | |
In office October 9, 1997 – January 20, 2001 | |
Ààrẹ | Bill Clinton |
Asíwájú | George Moose |
Arọ́pò | Walter Kansteiner |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Susan Elizabeth Rice 17 Oṣù Kọkànlá 1964 Washington, D.C., U.S. |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Ian Cameron (1992–present) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Alma mater | Stanford University New College, Oxford |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |