Susan Wojcicki
Susan Diane Wojcicki (tí a bí ní oṣu keje ọjọ́ 5, ọdún 1968 o si ku ni Oṣu Kẹjọ Ọjọ 9, Ọdun 2024) jẹ́ olùdarí ìdókòwò ara ìlú Poland-Amẹrika tí ó jẹ́ alákòóso YouTube láti ọdún 2014. Àkójọpọ̀ ọrọ̀ rẹ̀ jẹ́ $765 million ní ọdún 2022.[1]
Susan Wojcicki | |
---|---|
Wojcicki in September 2016 | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Keje 1968 Santa Clara County, Kalifọ́rníà, U.S. |
Iṣẹ́ | Business executive |
Title | CEO of YouTube |
Board member of | Salesforce Room to Read UCLA Anderson School of Management |
Olólùfẹ́ | Dennis Troper (m. 1998) |
Àwọn ọmọ | 5 |
Àwọn olùbátan | Esther Wojcicki (mother) Stanley Wojcicki (father) Anne Wojcicki (sister) Janina Wójcicka Hoskins (grandmother) Franciszek Wójcicki (grandfather) |
Signature | |
Wojcicki ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ ìmọọ-ẹ̀rọ fún ogún ọdún.[2][3] Ó kópa nínú ìṣẹ̀dá Google ní ọdún 1998 nígbà tí àwọn olùdásílẹ̀ rẹ̀ kọ́kọ́ ṣètò ọ́fíìsì wọn síbi gáréèjì ilè àwọn òbí rẹ, tórúkọ wọn ń jẹ́ Esther àti Stanley Wojcicki. Ó ṣiṣẹ́ bíi olùṣàkóso ìtajà àkọ́kọ́ ti Google ní ọdún 1999, lẹ́yin náà, ó jé olùdarí ìpolówó ọjà ní ilé-iṣẹ́ náà lórí ẹ̀rọ-ayélujára. Lẹ́yin tí ó ṣàkíyèsi àṣeyọrí ti YouTube, ó da lábàá pé kí Google rà á, wọ́n fọwọ́ sí àdéhùn náà fún $ 1.65 billion ní ọdún 2006. Wọ́n sì fi sípò alákòóso YouTube ní ọdún 2014.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "#34 Susan Wojcicki". Forbes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-08-23. Retrieved 2022-07-09. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "YouTube's Susan Wojcicki: 'Where's the line of free speech – are you removing voices that should be heard?'". the Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-10. Archived from the original on 2021-01-19. Retrieved 2021-01-16. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Connley, Courtney (2019-08-20). "YouTube CEO Susan Wojcicki: Here's what to say when men are talking over you at a meeting". CNBC (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-11-09. Retrieved 2021-01-16. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Susan Wojcicki |