Suzanne Olufunke Iroche tàbí Suzanne Olufunke Soboyejo-Iroche Jẹ́ òṣìṣẹ́ báǹkí ní orílé èdè Nàìjíríà èyí tí ó ń darí Finbank tí orílé èdè Nàìjíríà.

Ìgbé Ayé

àtúnṣe

Iroche lọ sí ilé ìwé gírámà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Queen's College, èyí tí ó wà ní ìpínlè Èkó àti Fásitì tí amọ̀ sí Unilag, lẹyìn èyí ní ọ lọ sí Kellogg School of Managemet ni Illionois.[1] Bákan náà ó jẹ́ Adarí àgbà fún ilé ifowopamọsi tí amò sí Globa Banki Directorate.[2] ọ sí wá lára àwọn elétò fún Pension Managemet Reform fún ilé ìfowópamọ́ United Bani God Africa, UBA.[3] Ó di mímọ kàà nígbà tí rògbòdìyàn bá àwọn ilé ìfọwópamọ́si ní orílé èdè Nàìjíríà, ìgbà yẹn ní wọ́n gba ṣé lé àwọn àgbà Adarí bánkì marun-un ni oṣù kẹjọ ọdún 2009, tí wọn sì fí àwọn márùn míràn èpò wọ, èyí tí òǹtẹ̀ sí wà láti ilé ìfọwópamọ́si Gbogboògbò tí ó ń jẹ́ CBN. Igbákejì Gómìnà, Sarah Alade ní ọ fí Iroche jẹ́ Adarí Bánkì Finland ní Nàìjíríà, èyí tí bí rọ́pò Okey Nwosu. Lára àwọn tí wọn jẹ Adarí bánkì mìíràn tí wọn rí lóyè náà ní CEO tí Union Bánkì, Dr. batu Ebong, tí Olufunke Iyabo Osibodu rọ́pò rẹ àti Cecilia Ìbẹrù tí John Aboh tí Oceanic Bank rọ́pò rẹ̀.[2] Ní ọdún 2019 ní wọ́n fí jẹ Adarí Àgbà ti amọ̀ sí Executive Director fún Ilé iṣé kàn tí ó ń jẹ́ United Africa Company Of Nigeria, UAC, tí ó èpò ẹni Awuneba Ajumogobia tí ó daṣẹ sílẹ̀ ni ipari oṣù keje.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. New CEOs resume immediately, who they are?, Babajide Komolafe, 14 August 2009, VanguardNGR, Retrieved 23 February 2016
  2. 2.0 2.1 CBN sacks 5 Banks Directors, Gabriel Omoh and Babajide Komolafe, 14 August 2009, VanguardNGR, Retrieved 23 February 2016
  3. Suzanne Olufunke Iroche, Bloomberg, Retrieved 23 February 2016
  4. Olawoyin, Oladeinde (2019-07-31). "UAC director resigns" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-10.