Sylvaine Strike jẹ́ òṣèré, akọ̀wé àti adarí eré orí ìtàgé lórílẹ̀ èdè South Áfríkà.

Sylvaine Strike
Ọjọ́ìbíPretoria, South Africa
Orílẹ̀-èdèSouth African
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Cape Town
Iṣẹ́

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí sì ìlú Pretoria. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Cape Town, ó sì gboyè nínú ìmò dírámà ni ọdún 1993.[1][2][3]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Strike jẹ́ adarí fún àwọn òṣèré ni ilẹ̀ iṣẹ́ Fortune Cookie Theater.[4] Ó jẹ́ ìkan láàrin àwọn olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ náà. Ó ti dárí àwọn eré bíi Miser (2012), Tartuffe (2017)[5], Tobacco and the harmful effect thereof (2016)[6]. Ní ọdún 2016, ó gbé eré Black and Blue kalẹ̀.[7] Láàárín àwọn iṣẹ́ tí Strike tí dárí ni Miss Dietrich Regrets (2015),[8] DOP (2019),[9] àti ECLIPSED (2019).[10]. Ó ti kópa nínú àwọn eré bíi Those Who Can't,[11] Black Sails,[12] Mad Dogs, àti The Hot Zone.[13]

Àwọn àmì ẹ̀yẹ tí ó tí gbà

àtúnṣe

Ó gbà àmì ẹ̀yẹ adarí tuntun tí ó dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Rosalie van den Gucht ni ọdún 2004. Ní ọdún 2006, ó gbà àmì ẹ̀yẹ Standard Bank Young Artist Award fún ipá tí ó kó nínú dírámà.[14] Ní ọdún 2010, ó wá láàrin àwọn èèyàn mẹẹ̀dọ́gbọ̀n tí wọn yàán kalẹ̀ fún Rolex Mentor Protégé Arts Initiative. Ní ọdún 2011, eré Butcher Brothers tí ó ṣe gba àmì ẹ̀yẹ láti ọ̀dọ̀ Naledi Awards.[15]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Sylvaine Strike receives France's top cultural award". French Embassy in South Africa | Ambassade de France en Afrique du Sud (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-31. Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. Middeke, Martin, ed (2015). The Methuen Drama Guide to Contemporary South African Theatre. Bloomsbury. pp. 81. ISBN 978-1-4081-7671-9. https://books.google.com/books?id=2ClBCgAAQBAJ. 
  3. Morkel, Toni (2010-01-01). "An interview with Sylvaine Strike". South African Theatre Journal 24 (1): 201–208. doi:10.1080/10137548.2010.9687929. ISSN 1013-7548. https://doi.org/10.1080/10137548.2010.9687929. 
  4. "About". Fortune Cookie Theatre Company (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Krueger, Anton (2019). "Revolutionary Trends at the South African National Arts Festival". In Eckersall, Peter. The Routledge Companion to Theatre and Politics. Routledge. pp. 47. ISBN 978-0-203-73105-5. https://books.google.com/books?id=UC2NDwAAQBAJ. 
  6. Stones, Lesley (2016-02-15). "Review: Tobacco, and the Harmful Effects Thereof". Daily Maverick (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-25. 
  7. Taylor, Victoria (2015-10-01). "Black and Blue returns to Jozi". Alex News. Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Sassen, Robyn (2015-06-16). "Underneath the star quality of Marlene Dietrich". The Mail & Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. "DOP, a mesmerising tale of an ordinary man". Bedfordview Edenvale News. 2019-12-29. Retrieved 2020-06-25. 
  10. BWW News Desk (2019-10-02). "Mental Health Awareness Takes Centre Stage At The Market Theatre". BroadwayWorld.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. MorneJK (2017-03-19). "Stars descend on SAFTAs red carpet: Here are the winners". Jacaranda FM. Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  12. "Julianna Margulies on outbreak thriller The Hot Zone, filmed in SA". Screen Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-17. Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  13. The Hot Zone (TV Mini-Series 2019) - IMDb, retrieved 2020-07-06 
  14. Hoho, Busisiwe (2020-06-21). "Sylvaine strikes again with The Butcher Brothers". www.grocotts.co.za. Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  15. de Beer, Diane (2011-03-08). "Top of the theatre charts". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)