Sylvester Madu
Sylvester Madu (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkànlá oṣù kìíní ọdún 1975) [1] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Anambra lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2]
Ìgbà èwe rẹ̀
àtúnṣeSylvester jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Anambra. Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ fún ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama kí ó tó kàwé gboyè ní University of Maiduguri, lápá àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀
àtúnṣeÓ ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó tó àádọ́ta lé ní igba (250)
Lára àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa ni;
- Power of Trust
- Scent of Passion
- Holy Cross
- The Shepherd
- The Generals
- Power of Love
- Tears of the blind
- Emotional Tears
- The Cat
- Ogbanta the family hunter
- Poverty
- Scent of Passion
- Runaway Bride
- Holy Cross
- Retaliation
- Death of Shita Rambo
- The Family
- The Illiterate
- Days of My Wedding
- Wedding Pandemonium
- To Love An Angel
- Different World
- Tears of the Blind [3]
- Dangerous Madman
- Born to Suffer
- Disclosed
- The Redeemer
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Pinterest (in Èdè Póláǹdì) https://www.pinterest.com/pin/624874517038899121/?%24ios_deeplink_path=pinterest%3A%2F%2Fpin%2F624874517038899121&%24android_deeplink_path=pinterest%3A%2F%2Fpin%2F624874517038899121&_client_id=nF-CnqNq5YgGUb2MHtNtFe0Ci0k5mazE3h-UcLFpZYVdFwtD9W8qS1DsI8ncx8dR&utm_source=168&utm_medium=2160¤t_page_url=https%3A%2F%2Fwww.pinterest.com%2Famp%2Fpin%2F624874517038899121%2F&install_id=5f393031&%24fallback_url=https%3A%2F%2Fwww.pinterest.com%2Fpin%2F624874517038899121%2F%23details&_url=https%3A%2F%2Fwww.pinterest.com%2Famp%2Fpin%2F624874517038899121%2F&_branch_match_id=880821295621297088#details. Retrieved 2021-01-21. Missing or empty
|title=
(help) - ↑ "Sylvester Madu: Biography, Wife, Movies & Net-worth". Schoolings. 2020-08-02. Retrieved 2021-01-21.
- ↑ "Sylvester Madu biography, net worth, marriage, movies and more". Naijabionet. 2020-07-19. Retrieved 2021-01-21.