Tòbágò
Tobago (pípè /təˈbeɪɡoʊ/) ni eyi to kerejulo ninu awon erekusu meji niinla to se Orile-ede Olominira ile Trinidad ati Tobago. O budo si apaguusu Omiokun Karibeani, ariwailaorun erekusu Trinidad ati guusuilaorun Grenada. Erekusu yi wa ni ode ile iji.
Tobago | |
---|---|
Àmì ọ̀pá àṣẹ
| |
Orin ìyìn: Forged From The Love of Liberty | |
Olùìlú | Scarborough |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | English, Tobago Creole |
Ìjọba | autonomous island of Trinidad and Tobago |
George Maxwell Richards | |
Orville London | |
Ìtóbi | |
• Total | 300 km2 (120 sq mi) |
Alábùgbé | |
• 2000 estimate | 54,000 |
Owóníná | Trinidad and Tobago dollar (TTD) |
Ibi àkókò | UTC-4 |
Àmì tẹlifóònù | 1-868 |
Internet TLD | .tt |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |