Tóbilọ́ba Àjàyí
Tóbilọ́ba Àjàyí jẹ́ Agbẹjọ́rò, ajàfẹ́tọ̀ọ́ abarapá ọmọ Nàìjíríà. Òun náà jẹ́ abarapá ènìyàn fúnrarẹ̀. Ó gba àmìn ẹ̀yẹ Mandela Washington Fellowship lọ́dun 2016. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí dìgírì kejì nínú ìmọ̀ òfin, International Law láti University of Hertfordshire, ní orílẹ̀-èdè United Kingdom. Lára akitiyan rẹ̀ fún ẹ̀tọ́ àwọn abarapá Ìran 2020 Nàìjíríà fún àwọn abarapá (Nigeria Vision 2020 on disabilities) àti òfin Ìpínlẹ̀ Èkó lórí àwọn abarapá. Ó ti kọ ìwé mẹ́ta.
Tóbilọ́ba Àjàyí | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oluwatobiloba Ajayi Eko, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Oǹkọ̀wé, Agbẹjọ́rò, ajàfẹ́tọ̀ọ́ |
Ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
àtúnṣeÀjàyí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí. Àwọn òbí rẹ̀ lọ́ra láti fi i sí ilé-ìwé nígbà èwe rẹ̀ nítorí pé ó jẹ́ alábarapá. Kò lè jókòó, dúró tàbí rìn lásìkò náà. Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́ta, ó sìn parí ẹ̀kọ́. Ó kẹ́kọ̀ọ́ dé yunifásítì nínú ìmọ̀ òfin kí ó tó dèrò òkè-òkun láti tẹ̀tsiwaju láti kàwé gbàwé ẹri dìgírì kejì, (Masters Degree) ní University of Hertfordshire.[1]
Àwọn akitiyan yàn isẹ́ rẹ̀
àtúnṣeNí ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ ní Mobility Aid and Appliances Research and Development Center.[2] Ó kópa nínú ètò Ìran ọdún 2020 fún àwọn abarapá (Nigeria Vision 2020 on disabilities matters), bẹ́ẹ̀ ló wà lára àwọn tí wọ́n kọ̀wé òfin ẹ̀tọ́ àwọn abarapá ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[3] She was awarded a Mandela Washington Fellowship in 2016.[4][5]. Lọ́dún 2017, ó ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ As of January 2017 Benola Cerebral Palsy Initiatives. Títí di February 2018[update] Ó ṣe àkóso àjọ "Let CP Kids Learn", èyí àjọ tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ àti ìdàgbàsókè àwọn ọmọ abarapá .[6]
Àwọn ṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣe- Inspirations. CreateSpace Independent Publishing Platform. 2013. ISBN 978-1-974596-80-5. https://books.google.com/books?id=QykItQEACAAJ.
- Who's With Me?: The Bible Meets Life-31 Days of Practical Christianity. Tate Pub & Enterprises Llc. 2015. ISBN 978-1-63418-386-4. https://books.google.com/books?id=Zjf2rQEACAAJ.
- Observe to Do: From Rhetoric to Real Faith. Tate Publishing & Enterprises, LLC. 2016. ISBN 978-1-68142-667-9. https://books.google.com/books?id=CogXjwEACAAJ.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe{{Reflist} {
- ↑ Adetorera, Idowu. "‘There is life after disability’". The nation. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Adebayo, Bose. "MAARDEC’s Ms wheelchair contest gives voice to the physically challenged". Vanguard. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Osonuga, Freeman. "A Nigerian Lawyer With Cerebral Palsy: My Encounter". The Huffington Post. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Precious, Drew. "The Presidential Precinct Announces 2016 Mandela Washington Fellows". Presidential Precinct. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Precious, Drew. "Tobiloba Ajayi". Presidential Precinct. Retrieved 16 November 2019.
- ↑ Dark, Shayera (27 February 2018). "Nigerians with disabilities are tired of waiting for an apathetic government". Bright magazine. https://brightthemag.com/health-nigeria-disability-rights-activism-96aa2cfef5f2. Retrieved 11 November 2019.