Tóyìn Adégbọlá

òṣèré orí ìtàgé

Tóyìn Adégbọlá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Aṣẹ́wó tó re Mẹ́kà ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1961. [1] Ó jẹ́ òṣèré sinimá Yorùbá, olùgbéré-jáde àti adarí eré ọmọ.orílẹ̀-èdè Nàìjíríà [2]

Tóyìn Adégbọlá
Ọjọ́ìbíOlúwátóyìn Olúwárẹ̀mílẹ́kún Adégbọlá
December 28, 1961
[ Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]], Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́
  • actress
  • producer
  • director
Ìgbà iṣẹ́1984 - present
Notable workAyítalẹ̀

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimá

àtúnṣe

Ó bẹ̀ré eré orí-ìtàgé Yorùbá ní ọdún 1984, [3] Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe Arts and Culture Council, ẹ̀ka ti ][Ìpínlẹ̀ Ọ̀Ṣun]].[4]

Ìgbé ayé rẹ̀

àtúnṣe

Tóyìn ṣe ìgbéyàwó pẹ́lú ọkùrin oníṣẹ́ ìròyìn kan tí ó ti di olóògbé. Àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì tí ọ́run fi jínkí rẹ̀ ni wọ́n ń gbé ní orílẹ̀-èdè Dublin àti Ireland , bákan náà ni ó tún ti ní ọmọ-ọmọ. [5][6]

Lára àwọn eré rẹ̀ ni

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control Àdàkọ:Nigeria-actor-stub