Tẹlifísàn tabi Àfigbéwòran (TV) je afigbebanisoro amohunmuaworan to un se igbejade ati to n se igbawole aworan arekoja, ki ba je alawo funfun ati dudu tabi ti alawo orisirisi.