Tọpó Àgbádárìgì
Ìlú Tọpó jẹ́ ìlú kán tí ó wà ní eré-kùṣù agbègbè ìlú Àgbádárìgì ní ìpínlẹ̀ Èkó, bákan náà ni Ìlú Tọpó jẹ́ ibi tí àwọn ajíyìn rere Kátólíìkì kọ́kọ́ gbin àgbọn sí ní ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 1845,[1] ibẹ̀ náà sì ni wọ́n kọ́kọ́ dá ilé ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ sí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Topo populated place, Nigeria". Nigeria. Retrieved 2018-12-11.
- ↑ "Make Topo-Badagry coconut plantation tourists site - Monarch". The Eagle Online. 2018-09-01. Retrieved 2018-12-11.