Tadelesh Birra
Tadelesh Birra ni a bini ọjọ kẹrin leelogun, óṣu April, ọdun 1975 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ Ethiopia[1]. Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye ti Marathon awọn óbinrin to da lori ere sisa to waye ni Edmonton, Alberta, Canada ni ọdun 2001[2].
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kẹrin 1975 |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia |
Erẹ́ìdárayá | Long-distance running |
Àṣèyọri
àtúnṣeTadelesh yege ninu ere awọn óbinrin ni Marathon ti Hannover to waye ni Germany ni ọdun 2003 ati 2004[3]. Ni ọdun 2009, Birra yege ninu Marathon ti Amman ni Amman, Jordan.